Yeye osun ajetunmobi

Yeye osun ajetunmobi

You may also like

Renue Plastic Surgery
Renue Plastic Surgery

I HELP WITH ROOTS AND LEAVES FOR SOLUTION TO HUMANS PROBLEM SOLVE

27/03/2024

OSHOLE gbarada


Ewe etiponla tutu oojo
Oga ooye kan
1k tuntun kan
igba olomori tabi Ike funfun kan
Ose dudu.

SISE RE:-a o gun ewe etiponla tutu oojo na ti yoo kunna dada, aowa gun mo ose dudu,
leyin eyi a o wa fi 1K yen tele inu igba olomori na tabi Ike funfun, aowa gbe oga ooye na le owo na lori, aowa ko ose ti agun yen le lori, a o wa fi omori igba na de tabi Ike yen, aowa gbe pamo fun ojo meje, leyin ojo meje odi lilo.

LILO RE:-aoma fi ose na we larolaro pelu kainkan ibile.

AKIYESI:-ki a to soro si eniyan la nwe ose yi atipe ti a ba nwe ose yi, a o ma se adura owo nlanla, igbakigba ti a ba nlo ise yi, agbodo sora fun agbere +2349114523239

25/03/2024

FUN ENITI NFI OJU KO OWU ALANTAKUN

Opolopo niwon ti fi owu alantakun de mole tosi gbiyanju lati je eyan pataki laye, sugbon kaka ki oro re yato, otun buru si ni, to siti so opolopo alfa di oniro loju re, nitoripe opolopo owo loti fi se igbiyanju ti aye re o kuro loju kan.. sare lodan ise yi wo odara pupo kio le bo ninu ide aye..

ISENA RE:- Ao fi owo alafia wa gba ito ti aba koko to ni owuro ki a to ba enikeni soro, ao fi ito bo oju ati ori wa, ao fisile sibe to bi iseju 10 -- 15 ki a to fo nu, Ao mase ni gbogbo igba.. Fun 3days odamiloju wipe ao ni fi ojuko owu alantakun mo..

IKILOPATAKI
tio bafe ki ise yii je fun o dada koko bami share ise yii si opolopo group kosi fi comment re se adura tio bawu o funmi nitori anfani elomi ni oro gbogbo yio di ayo ninu odun yii lase edumare +2348176778076

25/03/2024

ÈTÙTÙ AWỌN ÀGBÀ
Eran elede
a o ge si 16
ede pupa 16
obi abata 16 ao la okookan
re si meta meta
Ogede omini meta
ao ko eran elede tele awo ipese dudu,
ao da ede le lori
ao ko obi yen le
ao wa ko ogede si
ao fi iyere Osun Te Ifa osa meji
I I l l
I l
I l
I l
Ao wa se adura ti abafe si
ao da le etutu naa lori
ao gbe lo si orita meta to ba ngba ebo daada,+2348176778076

Follow page
Like comment share

17/03/2024

INITIATION TO IFA TRADITION
Initiation into Ifa and Orisa spirituality assists you in developing a deeper, closer relationship with your Orisa. During Initiation the energy/spirit/Ase of the particular Orisa you are seeking is transmitted to you through your Ori (head/inner spirit). This is done through several days of ritual, divination, and ceremony. The process of initiation allows you a deeper connection to your Orisa and activates the power of the Orisa that is within you. Initiation is usually done to support you in your life and in achieving your destiny. Walking with your Orisa gives you access to greater ability to live your life in harmony and provides access to the Orisa that governs your life and the world around you. When you choose the priest you would like to initiate with you are also choosing the family/Ile you will train and study with. To learn the ways of a priest takes many years of study under a competent Orisa and Ifa family. You can begin learning years prior to Initiation or after Initiation, Initiation with extensive study and training will prepare you for priesthood and gives you strength within your own spirit to navigate your life more successfully and connect to your Orisa.
Call me +2348176778076
Whatsapp+2348176778076

17/03/2024

OSE AJIGBARE
Eyi ni Osole Ajigbare ti mu bi million 3 wa todaju gbangba, Iwo ore mi, gbiyanju re ko fun mi ni abo Tori oogun ki gbenu iwe je o.....

ISE NAA NIYI
Ao wo tagiri to tobi daadaa ti osi ka aje. Ao wa pansa tagiri yi ti yio ni iho ninu, leyin na, ao wa ako eiye ega kan, eiye alapande kan, ori pepeye pelu atare aja gidi kan. Ao to gbogbo awon eroja yi yika (round) ori ako pepeye yi. Ao wa fi oba owo N1000 tuntun yi ka, ao we ni owu imule ti yio le daadaa. Ao wa gbe ise ti awe yi sinu tagiri tia pansa, leyin in na, ao fi ideri re de, ao wa fi owu imule we papo ti ara re ko ni tan ni ibikan kan, leyin na, ao
fi oti schnapps san inu ape ejoogun wa nu, tio ba gbe, ao gbe ise yi sinu re, ao jo ni ajo wo.

LILO RE: Ao da ebu oogun yi si meji. Ao da idakan si inu oti Lord, ao fi idakeji pamo, tia ba lo ida akoko tan, ao tun ma lo ida keji. Ao ma mu ni shot kan ni aararo pelu adura fun owo nla nla kiakia.

GBOLOHUN RE
Ega suuru, ega suuru, ibi ti ega ba fidi bale si, oja ni da, ki ile emi lagbaja omo lagbaja wa di oba aje ti tokunrin tobinrin yio ma na latoni lo. Oju mo ko ni mo, ki tagiri ka
ka aje tie, ki emi lagbaja omo lagbaja gba ire owo nlanla lani nidi ise ti mo yan laayo. Ki nje ifa aje nlanla loni. Biidan biidan ni alapandede nse un gbogbo. Ki ire aje,
oro, owo nlanla ma de simi lowo biidan biidan lati oni lo o.
O dase fun ranlowo pemi abi what app 08176778076
Canada

11/03/2024

TI IYAWO WA BA NJADE TABA FI ORUKA YI GBA NIDI HAAAAAAAA...
INA NI KOMO OJU ENI DA OOO..... .....
ABI KOJE OMO WA OBINRIN LAFI GBA NIDI NIGBA TO HUNLO ..
TI WON BA FE SUMO OKUNRIN KO KUNRIN ..WALAHI TALAHI MOFI ISE YI BURA GIDI
GAN.......NKAN OMO KUNRIN NA KONI GBERI RARA OOOO
AMO TI OKUNRIN BAFE SUMO OBINRIN OKO RE YIO GBERI AMO IYAWO WA ABI OMO
WA TI ADE TIFI ORUKA NA GBAWON ...HMMM
OKO OKUNRIN KONI GBERI RARA ...OOO....

EWE AMUNIMUYE
EWE INA
EWA KAKURE DIE
ORUKA OJE KAN......

AOLO AWON NKAN YI PAPO ..AOKO SINU IKARAHUN IGBIN KAN ABI INU IKE KAN
AORE ORUKA NA SINU RE FUN OJO MEJE GBAKO LEHIN OJO KEJE AOYO AOSA SIBI TI
KONIRIN ORUN RARA .......

AOKIBOWO FI GBA OBINRIN NA NIDI
MAFI SEKA OOOOO
OLORUN NBE OOOO..USE IT TO PROTECT YOUR SELF WITH YOUR OWN WIFE OR DAUGHTER ........+2348176778076

03/02/2024

IFA ASINA
(ogunda meji)
Iwe adie kan, ewe sawerepepe tutu, aogun mejeeji mo ose dudu, iseyi koni atare o, aofi iyereosun te ifa ogunda meji si ori ada (cutlas) aope ofore si, aowa po ose yen mo lori ada na, ori ada na sini yio magbe, aoma we ni igbakugba toba wuwa
OFORE:
Ona si, ona la, ona kiidi mo oloko, ona kiidi mo alada, ona kiidi mo onlo adie lati aro di ale, atole atole niki ire gbogbo ire aiye yi maatowa si odo mi lode ileyi, atole atole ni adie nto omo okababa, atole atole ni adie nto agbado, ada loni ki gbogbo ire gbogbo aiye yi maa da wa sodomi, ogunda meji loni ki ire gbogbo ode ileyi oma da girigiri wa si odo mi, sawerepepe ni efipe ire nlanla tinbe lode ile yi wa fun mi, (adua) mase ya alaimoore o
,+2348176778076

03/02/2024

Iferan tipatipa
Ti eyan ban lo ose yi,awon agbayo ma feran eni na won o ni ba nkan re je

A o wa ifun ako alangba mefa,a o lo kuna lori olo,a o lo ewe mafowokamomi,epo obo mo,a o po mo ose pelu ori,epo adin lai fomi si rara,a o ko ose na sinu fitila oloju merin,a o ma we sun lale lai jade mo,odara pupo.

Call +2348176778076
Whatsapp+2348176778076

Photos from Yeye osun ajetunmobi's post 22/01/2024

OSE ITAJA ATI IPARA RE TODAJU

Ejo mio fe ibere ti koni itumo oo, eniti o ba ta oja nikan ni ise yi wa fun, eyin onise owo eku ifoju sona, ise yin bowa.

ISENA RE:-
Ewe bomubomu eyo meta (3)
Ewe taba ibile eyo meta (3)
Aogun papo toba kunna aopo mo ose, aoko sinu ike funfun.
Koju bayi lo, ti ori eyan ba buru, toba we ose yi walai yio mari oja taa.

IPARA RE:-
Ewe ola, aolo yio kunna, aoda sinu turari six flower, aowa igbale ti afi gbale (broom) aose ori re lona merin, aoko sinu turari yen, aoma fi para ti aba we ose yen tan.
Whatsapp+2348176778076

Owale bai fun tita ooo

18/01/2024

Oshe anu tipa tipa ti gbogbo aye fin yonu siyan

Ise ti éwo yini awon onisowo
Ati awon Kara kata ati awon
Onishe ijoba ati awon alfa ati baba alawo
Ati awon pasito kosi éniti kole lo nibi iseyiyi damin loju de intun sishe iferan gbogbo aye ibiti éniyan bade ni won mon yonu si éniyan

Isenani…. Odidi ayele fun fun kan ati éwé dandan ati éwé atewogba ati éwé óla tutu ati éwé rerin komin ati éwé alubayida ati éwé sheshe fun ati éwé kori kosun tutu ati odidi atare pelu a*ofunfun opakan ati apoti kékére ni iwon ba

Shishe ishena… Agun gbogbo éwé na ninu odoo yatosi a*o ati odidi atare ati éyele ti abawa gun na dada awabo gbogbo épo ti owa Lara atare na ti inkanlan kosini ni ta danu nibi pe awa da sinu odo awa sheshe ju éyélé hun si ni aye awagun papo ti abati gun tan awafi a*ofunfun télé apoti na awagbe oshe na sini inu odiwiwe

Lilo oshena… Arolaro ni amon lo pelu gbolohun re

Gbolohun óshena ti abati fewé mose ba akoda aye moseba aseda moseba ayiti oluwwa gbe ayele lowo tori wipe éwé ólani loniki émin lagbaja ómó lagbaja ni oni éwé dandan loni ki gbogbo ohun ti émin lagbaja ómó lagbaja badawole komon yori si reré éwé atewogba loni ki gbogbo ómó araye montewo gbamin si dada éwé óla loni ki óró aye min lagbaja ómó lagbaja loni ki OLA si reré éwé rerin komi loni ki ati ómóde ati agbalagba ni ki won mon yonu si mon tori wipe atare kan kidi t**i ré labo totun tosi ni éyéle fin koré wole Lati oniyi lo ore lar lar ni ki omon wole min ooo tori wipe bi oku baku a*ofunfun ni bo ni asiri Lati oniyi lo ki asiri émin lagbaja ómó lagbaja mon bo ni ooooooo

Ikilo…. Ijoti abati pari iseyi kogbodo kan le mon

Iwoti obafe ki isheyi gefun óó comment and share pelu opolopo adua fun min

Fun iwoti obani anfani ati she iseyi fun rare iseyi owale fun tita Whatsapp+2348176778076

11/01/2024

Alaafia
Powerful good luck soap is available, its drawn and attract good to you, it's a blessing to you, may olodumare guides and bless each and everyone.. goodness wishes..Ase edumare 🙏🏽
Whatsapp+2348176778076
Call 09114523239

11/01/2024

*FAVOUR SOAP UPGRADED*

It's a WAY PAVER. This virtually paves way for you in EVERYTHING. When this is used, people can't just help but favour you (Family, visitors, friends, strangers, everybody)

Paves way for :
● Business
● For money
● Interviews
● Relationships
● Contracts
● Gifts
● Jobs
● Attention
● Brings general goodluck to you.
● General favour from men and women
Can be used by both men and women
Whatsapp me on: 08176778076
Call 09114523239

11/01/2024

AÁJÒ IMULẸ TI WON FIN DARI OORE SI EDÁ ENIYÁN

EROJA RE NIYI
adan kan
akọ alangba kan
atare odidi kan

AKỌSE RE NIYI :
Aojo papo lẹbu a
Ao wa lo kunna daada
Ao wa rosinu sinu ike/igo funfun kan

LILO-RE
Ao bu die senu ona iyara wa
Ao wa bu epo pupa si
Ao wa ro papo
Ao wa fi ahon laaa nilenle
Ao lo sun
Bi ao se malo niyen

SE AYEWO LORI ORO AYE RE, LORI ISEDA RE KOLE MO IRU AYANMO TO GBE WAYE ATI ONA ABAYO
Whatsapp+2348176778076
Call 09114523239

09/01/2024

*FAVOUR SOAP UPGRADED*

It's a WAY PAVER. This virtually paves way for you in EVERYTHING. When this is used, people can't just help but favour you (Family, visitors, friends, strangers, everybody)

Paves way for :

● Business
● For money
● Interviews
● Relationships
● Contracts
● Gifts
● Jobs
● Attention
● Brings general goodluck to you.
● General favour from men and women

Can be used by both men and women

Whatsapp me on: 08176778076

02/01/2024

EYONU AWON AGBA

AIDAN KAN
ODIDI ATARE KAN

LO KUNNA DADA AO TENI FA EJIOGBE AO PE GBOLOHUNRE SI ..

Ohunre:-

Elarowa3*
Ifa mope ejiogbe ni baba ifa
Emi l-l ni mo pe iwo ejiogbe baba ifa wele loru loruko tanpe iwo iku
Wele loruko tanpe iwo arun ,
Owele wele ni oruko tianpe iwo asasi , olokun emi loruko tianpe eyin iyami osoronga eyin leye soso ori oro eyin lejoko talakara maraeni ra akara , esi ni jeki alakara kota bi ale balee ,gbogbo eye ndarijo sorigi aidan ibe ni olodumare ti nran se siwon pekin lense lori igi aidan, eleyin koni bale igi ree keje eso ree emi l-l moje eso aidan loni yii ooo emase fi owo aburu yin kan mi mo kiesi ma ba nkan mije mo
Ao ma bu ebu sinu epo ogere fun lila ...
Lalalee, fii comment re dupe
Whatsapp+2348176778076

02/01/2024

ÍFA ORÍRI TI A FÍ N GBA NKÀN NI TIPÀTIPÀ

ASIRI JU ASIRI LO BE SINI ASIRI LE GBE ASIRIMI, MO SOYI MO DAKE NA🤣🤣🤣

SISERE
óga Àaye Ibíle Meji, Ólori Owo Ilu Ti Á Wa, Ewe Abamóda Onigàga Marún Merin, Eyin Àdie Ororo To Mo Daada, Awóran Eniti A Fe Lo Fun ( Ti O Bà Ni Aworàn Ni O ) Ti Ko Ba Ni Ko Si Wàhala O, Éwe Tabi Ora Ti Ategun Gbé Lati Ona Jinjin, E Je Ki A Lo Ko Oje ( ) Ki A Fi Ko Orúko Eni Naà Si Inu Paper Fúnfun Kan, Ti Eni Naa Ba Ni Awóran Ki A Fi Suuru Si Felefele Ara Àworan Yen Ki A Wa Fi Ojé Yen Ko Orúko Yen Si Eyin Aworan Re, E Je Ki A Gbé Oga Kan Sile Ki À Fi Aworan Yen Han Ki O Gba Awo Re, E Je Ki A Sare Le Oga Yi Mole Ki O Gbe Aworan Yi Lo Sorun, É Wa Ba Mi Ge Ase Oga Yi Ati Ahon Re, E Ba Mi Ko Sinu Awóran Yi Ki E We Daada, E Tun Ba Mi Fi Owo Ile Okéere Tabi Ti Ilu Wa Hàn Oga Keji, Ki Ogà Yi Naa Gba Awo Owo Yi, E Sàre Ba Mi Ki Awóran Ti A Ka Yi Bo Enu Oga Keji Yen Ki A Wa Di Ni Owu Imule, Ao Dàniyan Si Pelu Oruko Ti A Ko Si Ara Awóran Yen, Ao Wa Ba Mi Ko Éwe Abamoda Mewa Tele Ape, E Je Ki A Fi Owo Yen Le Lori, Ewe Ti Aja Gbé Lo Soke Tabi Ora Ti Ko Kan Le Yi, E Ba Mi Fi Le Ori Éwe Yi, E Wa Bà Mi Gbe Oga Ti A Di Yi Le Lori Ati Eyin Ororo Kan Pelu Atàare Kan, Ao Wa Ba Mi Da Ewé Mewa To Ku Bo Mole, E Je Ki A Jó Ki A Wa Lo Ko Kunna Dàada, Ki A To Ko Ni Ori Olo, E Je Ki A Te Ni Ifa Ejiógbe, Ki A Ba Ni Gbólohun, Ao Wa Ba Mi Da Si Ona Meje, Eyin Oróro To Ba Mo Daada Méta Meta Ni A O Ma Fi Je Ni Ojo Kookan Pelu Aniyan, Leyin Ti Nkan Naa Ba Te Wà Lowo Tan, E Je Ki A Lo Fo Eyin Ororo Meta Si Orita Meta Ti Ese N Gba Lo Gba Bo, Bi Beeko O Seese Ki Eniti A Lo Awóran Re Ma Ri Wa Ni Oju Ala Ni Gbógbo Igba O, Eyi Si Le Fa Akoba Ti O Ba Pàda Ti Ese Ilé Bo..oforé...ifa Mi Oriri, Oriri Ni Ifa Mi, Iji Ja Ni Para Ó Ja Ni Poro, Sebi Ategun Ni N Gbe Àba Oga Fun Olodumore, Ki Atégun Wa Sare Lo Gbe Aba Ti Emi Lagbaja Da Yi Fun Olodumore Ki Làgbaja Se Nkan Bàyi Bayi Fun Émi Lagbaja O, A O Dàruko Nkan Ti A Fe Ki O Se.
Whatsapp+2348176778076
Call 0911 452 3239

29/12/2023

IFA EBE TA FIRI OWO IROSUN OSO.

Eyele dudu kan, eyele funfun kan,iye agbe kan, iye aluko kan, ikodide kan, ao ki iye kankan bo idi eyele na, ao koju won sira ninu ape ijogun , ao fi iye kan toku sinwon larin, ao wa oju malu mejeji,ao ko le lori, ao wa opolopo alubosa funfun, ao fi bo mole, ao jo, ao lo kunna, ao da ebu yi sinu opon ifa,ao te ni odu irosun oso,
l l
l l l
l l l
l l l l

Ofore: Abebe -lu- kebeke lan pe oso, alawuruku-nisan lan pe sopona, ona yaya komo awo oribilo lan pe oya, jefun jedo lan pe eyin iyami osoronga, ke yaa gbarajo ke de mi lade, ke gbarajo ke la mi, ke pokikimi kaye gbo, bi alubosa ba wolu oorure a gbalu kaan, ki okiki mi gbalu si rere, iko ni ke fi kore mi wa,iko de omo oni yebe, aluko ni ke fi kore mi bo, agbe de elewu idoro, ifa wa doro aje re bomi oo, emoje kose, emoje koye, ojo eniyan kin ye lara malu irosun osos ooo ifa jade motidi osole gbogbo eleye aje,ki mo rija toso taje mo oo. Ao ro sinu ike funfun kan ,ao ma fi fo eko tutu mu, tested ok

Whatsapp+2348176778076
Call 0911 452 3239
Gmail : [email protected]" rel="ugc" target="_blank">[email protected]

26/12/2023

Thanks for being a top engager and making it on to my weekly engagement list! 🎉 Adey Kola, Sherif Aro, Olayiwola Arigbabuwo, Akinde Olusoji Emmanuel, Aderemi Singer, Oyebode Samuel, Omonla Rahmon, Pacôme Bello, Rahmon Kolawole, Folake Jumoke

23/12/2023

🦠🦠EBE AWON AGBA TO DAJU🦠🦠
Anfani gidi re fun tako tabo, mio femo iru awon agbalagba ti eba se dandan niki won dari jina kiwon si tu gbogbo ide buruku Toba wa lara WA danu

Ao wa odidi eso aidan eyo kan,ewe orijin die pelu odidi atare eyo kan

Aowa jo papo aowa AO lo Kunna daada aowa ro sinu igo kekere kan

Aoma fi epo lo ni aaro kutukutu

Aofi oyin lo tio badi osan

Aowa maa fi adi lo lale

Bi aose malo iseyi niyi lojo jumo iseyi dara gan fun ebe awon agba eje kia lo gbiyanju re ni kiakia

Ise yi kere koni ni itumo loju yin,sugbon oun je bidan

Ki ato ma sope ogun kan ko confirm abi ogun kan kin dahun nje ati se ayewo ati iwadi awon nkan wonyi, nitori bi elomi se na Owo gidi Lori ogun otun daku isoro.iwadi se Koko ki aye fi ogun Inu rirun wo Ori fifo
Whatsapp+2348176778076
Call 09114523239

23/12/2023

ISE TI IYAWO WA BALO YAN ALE NITA NSE NI OJU ARA YIO MAA YUN GIDIGAN NIO ODIGBA TOBA JEWO NKAN TO SE KATO FUN NI ERO RE NI KETE TABA FUN NI ERO RE LO MA STOP..

Odidi eyo werepe kan
Odidi atare kan
Ori
Ose dudu

Sisere ++++odidi eyo yerepe kan,odidi atare kan,ao jo papo
Ao po idaji mon ori
Ao po idaji mon ose
Ao fi ti olose pa opamose wa fiba obinrin naa sun,toba lo doko nita nse ni powerhouse yio maa yun afi ti aba fun ni ero re

ERO RE ++++Ao fun ni ti olori yen yio fi pa abe re tabi kafiti olori pa opamose wa kafi ba obinrin naa sun koni yun mon....

NOTICE+++IWO TOBA LO ISE YII FUN IYAWO ONIYAWO TABI OFI SE IKA OOGUN LAKAAYE LOMA PA ENITOHUN ASEEE.

Fun iwoti obafeba ifani gbolohun lori ohun to sokunkun si oro aiye re pemi tabi ki message mi lori watapp
Ibanisoromi. 09114523239
Watapp mi ree. 08176778076

22/12/2023

ORUKA AWON AGBA TIO NSISE ANU
IWO TIO BA NI ORUKAYI MOKIO KU ORIRE OWULO FUN OMO YAHOO
AMA FIN GBA OWO NI

AWON NKAN RE

Ako eye ega eyo Kan
Oruka elo eyo Kan tabi eyi tia balelo
Ewe amunimuye ojo
Odidi atare kan
Omi agbon

SISE RE
aofi ewe amunimuye ojo ye we oruka ye radi, ti ORUKA ye oniranma, AWA tibo inu eye EGA yi ni aye , awajo pelu odidi atare kan

LILO RE
aofi oti abi omi agbon lo ebun ti ajo ye lekan soso
AWA ti ORUKA ye bo ibi owo ti abama loju lati figba nkan

ise yi daju Debi wipe kosi eniti yolo ti koni babee ( ise awon agba to confirm gan niooo
Kio bale je fun o fi comment ranse si mi

Fun ibere abi alaye lekunrere tabi ona abayo Lori eyikeyi isoro todoju koo,+2348176778076

Photos from Yeye osun ajetunmobi's post 19/12/2023

🦠🦠EBE AWON AGBA TO DAJU🦠🦠
Anfani gidi re fun tako tabo, mio femo iru awon agbalagba ti eba se dandan niki won dari jina kiwon si tu gbogbo ide buruku Toba wa lara WA danu

Ao wa odidi eso aidan eyo kan,ewe orijin die pelu odidi atare eyo kan

Aowa jo papo aowa AO lo Kunna daada aowa ro sinu igo kekere kan

Aoma fi epo lo ni aaro kutukutu

Aofi oyin lo tio badi osan

Aowa maa fi adi lo lale

Bi aose malo iseyi niyi lojo jumo iseyi dara gan fun ebe awon agba eje kia lo gbiyanju re ni kiakia

Ise yi kere koni ni itumo loju yin,sugbon oun je bidan

Ki ato ma sope ogun kan ko confirm abi ogun kan kin dahun nje ati se ayewo ati iwadi awon nkan wonyi, nitori bi elomi se na Owo gidi Lori ogun otun daku isoro.iwadi se Koko ki aye fi ogun Inu rirun wo Ori fifo

Whatsapp+2348176778076

18/12/2023

ERO OFA TODAJU, ALELO FUN ENI TI WON TI TA LOFA, ATUN LELO TELE LAI TI JEPE WON TAFA SI WA.

Egbo igi a*ofeyeje, ao fi omi fo yepe benu, ao fi sibi kan ko gbe dada, ao sa kekeke ao ko sinu ororo mispariss nla kan, ninu lofinder mispariss lao ko si o, ao wa de, ao gbe pamo fun ojo meta, kotodi ojo keta yo ti mapon, yo ti toro, yo ti yipada si pupa.

Lilore::;; Eniti ofa banbe larare ao ma fun ni omo ideri mispariss kan laro, okan kale
Whatsapp+2348176778076

18/12/2023

ASIRI OLA KI ONA OWO LE LA KANWA.
Ako ati abo eye ega tope daada tutu tabi gbigbe, owo eyo mesan, ewe ola, ewe sawerepepe ati odidi atare kan, e ko gbogbo re sinu fitila oloju merindinlogun, inu re ni e ti ma jo, e lo kuna daada lori olo, ki e mafi milk lo larolaro. Hmmm, ise yi nilo eyonu, tude ati imunle lara.
ISEYI DAJU FUN OWO, OKIKI ATI CONNECTION. Dupe ki o bale je fun

Whatsapp+2348176778076

18/12/2023

ETO ADURA LATI SO ENIYAN DI OLOKIKI SI RERE
LORI ISE TI A NSE
Ao lo wa iyepe ile Oba olokiki meta, ojulowo ileke iyun, iyepe
okun, osa pelu ori owawa to ban i irun lori, a o gun gbogbo re
papo, ao fi omi iho inu igi po papo pelu oyin igan gidi, ao wa fi
photo wa tele inu awo tanganran funfun eyiti afi egungun se, a o
wa ko ose na le lori, ao wa gbadura si bayi pe: Oba olugbeniga
loju elegan, ma sai wag be emi omo re ga ni ilu yii ki gbogbo
araye gbo okiki mi sir ere lori ise ti mo nse nitoripe akii fowo
boo go ojo, enikan ki fowo boo go orun, ma gba fun ota lati fi
owo boo go mi mole lori ise ti mo nse nitoripe bi owawa ba pe
igba ninu igbo eyo kan soso lo ma han ninu won, emi nikan ni
ki okiki mi kan sir ere loni nitori omikomi kan ki bori olokun,
odo kodo kan ki bori olosa, Oluwa je ki ogo mi tayo ti awon
elegbe mi lori ise ti mo nse ki emi na le lu aluyo sir ere. Amin
A o ma fi ose na we ni ekan lose (Thursday), ao si ma kan oyin
diedie sinu omi iwe ki a to we, ODAJU
Whatsapp+2348176778076

18/12/2023

ASIRI IFUNRA AWON JAGUNJAGUN LAYE ATIJOO SAKA

asiri leyi kise ogun,ajetele nitori ojo idagiri ojo iwaju
Ti aburu bafe sele ni ayika wa tabi agbegbe tia wa arawa yio ma tutu ni. Kia tete kuro layika na,eyini awon agba ijohun ana fi nse asiri agbara.
NOTED dupe kiobaleje bina funooo
ISENARE
odidi alakan oiye Kan, eko elewe Kan
Ao bo eko ewe re kuro, ao fi alakan oiye yi sinu abo tofe ao fi eko yi si legbe ao fi apadi tabi ikoko amo bomole di aro ojo keji...yio tije eko na,awa na yio je eko ajeku yi laro kutu ai laifohun ni Hoho.
08176778076

18/12/2023

MARAN
Eleyi ni yio je idena fun enikeni toba fe na e ni nkan
Oruka wa o, agba sinwin wa,agba yaro wa, agba wo wa,subusere na Beni agba sare wa tiwa ma sa kakiri ilu, agba mumi na wa Beni awon onde Anapa,ana yagbe,ana gbo bi aja orisirisi ni awon ogun yi
Ogun yini kio lo se Sara majeki enikeni o disgrace (idojuti) e ...
Iru ako alangba meta ati Ori ako alangba meta ao kosi inu ape ao lo orogbo mefa kuna dada ao ko lewon Lori ao fi oko atare Kan jo ao lo kuna ao fi sin gbere yipo inu, yipo itan mejeji
Opo eyan lelo ninu etu yi ,,, enito bafi ogun na e,enina yio ge ika abamo je ni kiakia
Whatsapp+2348176778076

17/12/2023

OSOLE OWO KIAKIA.OMO YAHOO
Owo dollar kan.eye alapadede kan.odidi atare kan ao jopapo ti aba jotan alo tiyio kunna dada afi oti Snapp lo ni agokan oru.ni ekan ni ooo. Whatsapp+2348176778076

17/12/2023

OSHOLE OWO TO GBONA UMMM ISE NLA
MO BURA PELU ISE YIN
AT LAST MORI ISE YI SE
MO TI WA LENU RE LATI TI BE OSU OSE MEJI
TO RI WIPE
AWON ERONJA ISE YI LAGBARA PUPO KO
TETE SE RI, RARA
OKETE OOJO
AWO LILI KAN
TAGIRI KAN
1000 MARUN
ATARE KAN
AJAOO
IGBIN MEJI
EHANA OLONGBO KAN

TI ENYAN BA SE RI ISE YI SE
ENIYAN RI OWO BI (CBN) NI
ETUTU
IMULE
ASINA/ATUDE
IPESE AWON AJE
ISE YI NI MO SE FUN ONI BARA MI KAN NI BI
ODUN MEJI SEYIN, O WA NI USA BAYI1
ISE NLA NI OO
ISE YI KO SI ORU LATI OSE KAN, KI MO BE
AWON HUNTER WIPE KI WON BA MI WA
AWON INKAN YI
ISE YI JE ISE TO MO FE SE FUN ONI BARA MI

Mofi ifa bura si ogun daju gidi gidi gan fun eniyan ti ko ba le se ise yi fun Ara re ko messages me Lori facebook bayi bayi kal le soro Lori e opolopo awon eniyan Ni mo ba se ogun to si je
Message me Lori facebook bayi bayi to ba Fe se ogun na
Tabi ko Whatsapp me +2348176778076

17/12/2023

*ÌWÚRE ÒWÚRỌ̀ ỌJỌ́ ÒNÍ*

Nkàn mẹ́ta l'ọdẹ kìí pa:
Ọdẹ kìí pa asán,
Ọdẹ kìí p'òfo,
Ọdẹ kìí p'àdánù,
Ẹ̀yin Ọmọ Bàá mi l'óòtú Ifẹ̀ ,
Ẹ kò ní p'asán,
Ẹ kò mà ní p'òfo,
Bẹ́ẹ̀ni , ẹ kò sì ní p'àdánù o.

Gbogbo ara ni ṣẹṣẹfun fií nṣ'ajé l'ójojúmọ́ .
Ajé á máa jẹ́ ti yín l'ójojúmọ́ .
Ìná kòní tán ọwọ́ yín .
Ojú kìí pọ́n iṣin àìlà .
Ojú kò ní pọ́n yín .
Ibi ọká bá dúró sí ,
Ni oúnjẹ òòjọ́ rẹẹ̀ ńbáa .
Ibi erèé bá wàyàmì sí ,
Ni oúnjẹ òjòó tirẹ̀ máa ń báa .
Oúnjẹ òjòó yín kò ní wọ́n yín .
Aláàánú yín kò ní jìnà sí yín .
Ẹ ó ma rí ná.
Ẹ ó ma rí lò.

Àṣírí ẹ̀kọ kìí tú l'ójú ewé ,
Àṣírí yín kò ní tú .
Ekanna owo lo nbo asiri owo.
Èkáńná ẹsẹ̀ ló ń bo àṣírí ẹsẹ̀ .
Alàṣírí á máa b'àṣírí yín .
Gbogbo igi tí elégbédé bá ti fi ọwọ́ kàn ,
Dídún ló ń dún .
Gbogbo ohun tí ẹ bá ti dá ọwọ́ lé ,
Àṣeyọrí rere láá ma jẹ́ .
Àṣe dànù kòní tọ́ síi yín o.
Gbogbo ohun tí ẹ bá na ọwọ́ sí ,
Ire lá ma já sí.

Àlàáfíà á máa báa yín gbé .
Kéwekéwe kò ní kóo yín l'ọ́mọ lọ.
Aboyún ilé á bí wẹ́rẹ́.
Àwọn àgàn á t'ọwọ́ àlà b'osùn .
Ẹni tó ti bí kò ní yàn kú .
Jẹ́ngbọ́rọ̀ ni orúkọ àwọn ọmọ yín yóò máa jẹ́ .
Ẹ kò ní t'ilé ru òkú já'de ,
Ẹ sì ní ti òde ru òkú wọ'lé yín .
Fọ́fọ́ ni ilé omo ayò máa ń kún .
Ilé yín á máa kún f'ọ́mọ rere ni ò .
Ẹ kò ní fi àìsàn l'ògbà.
Bẹ́ẹ̀ni , ẹ kò ní ká góńgó s'ayé.
Ogun àdánìkangbélé kò ní jẹ́ ti yín .
Bí ẹ bá pe ìkan,
Ogún á jẹ́ yín .
Ire gbogbo á wá yín rí .

Ayé yín á r'ójú,
Ọ̀nà yín á r'áyè .
Olùlànà , á l'ànà ire fún yín ,
Ẹ kò ní ná ìkan tán
Kẹ́ẹ tún tó tún rí òmíràn .
Owó á máa bá a yín gbé.
Ẹ kò ní bùrìn bùrìn ,
Kẹ́ẹ tún wá jó mùkẹ́mùkẹ
Ẹ kò ní sínwín,
Atẹ̀gùn burúkú kò ní fé sí yín tọmọtọmọ.
Ẹ kò ní kú kẹ́ẹ tó kú .
Ẹ kò ní f'ara gbàrùwẹ̀.
Ẹ kò ní bá wọn d'ódò láì pọn'mi .
Èdùmàrè á ṣe ti yín l'áṣepé .
Gbégbé kìí gbé s'óko ìwáje,
Ase ni tedumare!!!
Come for spiritual healing this life is not for sleepers ,wake up so that you not remain the same thing,
contact us today to put remedy to your problem
WhatsApp +2348176778076

Want your business to be the top-listed Health & Beauty Business in Ijebu Igbo?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Videos (show all)

Oshe anu tipa tipa ti gbogbo aye fin yonu siyanIse ti éwo yini awon onisowoAti awon Kara kata ati awonOnishe ijoba ati a...
Oshe anu tipa tipa ti gbogbo aye fin yonu siyanIse ti éwo yini awon onisowoAti awon Kara kata ati awonOnishe ijoba ati a...
*FAVOUR SOAP UPGRADED* It's a WAY PAVER. This virtually paves way for you in EVERYTHING. When this is used, people can't...
OSOLE POWDER FOR NEW YEAR AVAILABLE+2348176778076
🦠🦠EBE AWON AGBA TO DAJU🦠🦠 Anfani gidi re fun tako tabo, mio femo iru awon agbalagba ti eba se dandan niki won dari jina ...
#likeforlikes #FacebookPage Available dm Whatsapp+2348176778076
OSOLE FOR ANYONE WHATSAPP ME+2348176778076#FacebookPage #follow #followus #comment #likeforlikes #sharethelove
OSHOLE OWO TO GBONA UMMM ISE NLAMO BURA PELU ISE YINAT LAST MORI ISE YI SEMO TI WA LENU RE LATI TI BE OSU OSE MEJITO RI ...
Meet the most trusted traditional herbalist  who treats almost 77 deaseses and also helps in any other kinds of spiritua...
Meet the most trusted traditional herbalist  who treats almost 77 deaseses and also helps in any other kinds of spiritua...
It help business people and salary earnings to see big money from work or business partner or friends, Whatsapp +2348176...
Meet the most trusted traditional herbalist  who treats almost 77 deaseses and also helps in any other kinds of spiritua...

Category

Telephone

Address

Ijebu Igbo
120101

Opening Hours

Monday 09:00 - 17:00
Tuesday 07:39 - 18:00
Wednesday 09:00 - 15:00
Thursday 09:00 - 19:00
Friday 09:00 - 20:00
Saturday 09:00 - 16:00
Sunday 09:00 - 18:00

Other Medical & Health in Ijebu Igbo (show all)
Baba Araba Baba Araba
No 33 Atan
Ijebu Igbo, 120105

Ogun state

Bodied by ewawunmi Bodied by ewawunmi
Oke Sopen Street
Ijebu Igbo

Expert Weight Gain And Weight Loss

Misic Guftrends Misic Guftrends
No 33 Oyindun
Ijebu Igbo

Jawesola Traditional Herbalist Jawesola Traditional Herbalist
No2. . . Agbola Onala Street
Ijebu Igbo

Chief Priest SKD Chief Priest SKD
Ijebu Remo, North Local Government Area, Ogunmogbo Township.
Ijebu Igbo, 120105

I am the water that has no anemy (nmiri eweilo okalakwu igbaraim) omenana igbo Ron' in my vein

Herpes Permanent Cure Herpes Permanent Cure
108 Ijebu Ode
Ijebu Igbo

This Herbal Medicine Is A Combination Of Roots And Herbs To Cure Herpes Virus Permanently Contact +

Herbalist Herbalist
Ogun State At Ijebu Igbo
Ijebu Igbo

Hello my people is me ifalase herbalist am here tell you people that don't West your time in this 20

Dr. Isibor Dr. Isibor
45 Samson Odugbesan Street, Oke-Ala, Ososa-Ijebu
Ijebu Igbo, 12001

Human papillomavirus (HPV) WhatsApp contact +2348050495479

Awogbemi Awoleke Awogbemi Awoleke
Ijebu Igbo

I am the great spiritualist man helping people, in terms ) i do ritual without using human being or

Herbalist Abumere solutions centre Herbalist Abumere solutions centre
Ijebu Igbo
Ijebu Igbo

Ifadamilare ewetola Ifadamilare ewetola
Adeboye Road Ijebu Igbo
Ijebu Igbo

Ifa damilare ewetola herbalist