Asiwaju bola Ameed tinubu for president 2023,

.

December 6, 2021 22/12/2021

December 6, 2021

Timeline photos 26/03/2021

ebawa dowo po loni eoni kabamo ilese duro lori iberu olorun ati otito nitori kristi ni apata wa. nile se oluwafemi obanijesu Estate agent,awon ileyi wafun lati daoko ati fusinsin nkan ni owopoku tkonini lara rara, #300.000 per acer,ekan siwa loni ese pupo aretiyin ooooooookkk

08/03/2021

Our radio program is coming up this Tuesday night at Root FM 97.1 station by 08:15 pm to 08:30 pm I want you to listen to the program and comments on its.
Mo fe ki e teti si eto wa ti o bo wa ni ose yi ni ale ojo isegun ni Root FM 97.1 ni Dede agogo Mejo koja iseju medogun si agogo Mejo abo Mo fe ki e teti si eto naa ki e si fesi si.

03/03/2021

Ekaro gbogbo eyin eniyan Olorun lori afefe loruko JESU yio dara funwa aori anu Olorun gba kile oni tosu amin loruko JESU Oluwa wa
Adura itun sile lafe gba loni yi,
Sope ni oruko JESU Oluwa tun ayemi sile kuro ninu ide aye loni loruko JESU Amin
Loruko JESU Oluwa tun ogo ayemi sile kuro ninu ide aye loni yi loruko JESU Amin
Ni oruko JESU gbogbo ogun ipinle toja ayemi logun to di ogo ayemi lowo tikoje kodi mimo fun aye loruko JESU Oluwa emaparun loruko JESU, gbogbo eyin agbara ile baba ati tile iya mi to damu ogo ayemi oya emaku loni loruko JESU Amin,sope oluwa yanda ogo ayemi fun mi loni loruko JESU Oluwa wa amin sope gbogbo eyin arogo bogoje ninu ninu iran mi ati ninu ayeyi emaku loni loruko JESU Amin
So majemu ajide gbemi dide loni togotogo ninu isemi loseyi ati ninu osuyi loruko JESU Oluwa wa amin,oto akoko eyin oluranlowo ayemi ewami ri loni loruko JESU Oluwa wa amin, sope oluwa bo a*o ogun kuro tofogun ja aye kuro larami loni ni oruko JESU Oluwa wa amin, sope ni oruko JESU Oluwa womi ni a*o ogomi pada loni loruko JESU Oluwa wa amin sope oluwa Olorun majemu la ipinle ayemi koja loniyi kobami pa gbogbo ogun ipinle toyo ayemi lenu run patapata loruko JESU Oluwa wa amin fun ibere tabi amoran epe sori nobayi 08025439928/08167132511, bobari amin 101 se loruko JESU yio dara fun ooo loni yi ounse ayo re yio je fun ooo loruko JESU Oluwa wa amin

15/01/2021

Ekaro gbogbo eyi omo Yoruba nile loko nirin ajo, Pataki oromi taroyin ni wipe eje komu isokan wa le pinpin fu ipin nu ipo ARE fu odun 2023 lati isisiyi lati fohun sokan ati fa enikan soso kale fu ipo ARE ejo, tabari eniti sineto bola ameed ti se lonakan tabi lona miyi mobayi loruko Oluwa efi owo wonu keje kagbe oro ona eranti eniyan, eje kajo sowo awa omo Yoruba papo lati fa bola ameed kale fun ipo ARE yi ni odun 2023 ase pupo

04/01/2021

Ekaro gbogbo eyin ololure asiwaju bola ameed tinubu, ebami so fun bola ameed pe koma beru lati jade fun IPO ARE ORILE EDE YI NI ODUN 2023,SUGBON EFI OLORUN SIWAJU IRIN AJO NA

Want your public figure to be the top-listed Public Figure in Ogun?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Category

Website

Address

Kobape Abeokuta
Ogun
Other Public Figures in Ogun (show all)
De Bright.com De Bright.com
Ijebu
Ogun

ASA oyoyo world wide ASA oyoyo world wide
Ogun

Happy to meet you here �

Odueko Olumide John Odueko Olumide John
Ogun

POLITICAL, SOCIAL, AND ECONOMIC ACTIVISM, PROMOTION AND ADVANCEMENT FOR BETTER SOCIETY

Dr lucky Osaka Dr lucky Osaka
Sango Otta
Ogun

My husband left me for another woman 😭 and I was heart broken 💔 and devastated. But on a good day

Miss Akesan 2019 Miss Akesan 2019
Dabira Street, Iperu Remo
Ogun

Better bethel Better bethel
Sango Otta
Ogun

Trust yourself 💜💜 better days ahead

Apostle J.O ALAHA Prayer page Apostle J.O ALAHA Prayer page
Comforter Tabernacle Jagunnan Village Via Olodo
Ogun

The purpose of this page is for the people that want to talk to Apostle Alaha or need a prayer

Fela Shenex Fela Shenex
Alagbado
Ogun

Am just happy with now open pages. Fela Nation

Catching cruise and having fun Catching cruise and having fun
Ejio, Arigbajo
Ogun

Randlestv Randlestv
Ogun

Entertainment

Ogunfadeke Abigi Ogunfadeke Abigi
No1 Ita Ti Kelu
Ogun, 23401