Omo Aroge Tv
Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Omo Aroge Tv, Public Figure, .
This is for 555 people online now - You will be the first person to break the york of travelling abroad in your family.
من لم يمت بصيف مات بغيرء
Olohun joo mafi iku toyawo pawa Amin oh
Barkah jummah more of it bijahi rosuulullah 💋❤️
Ìse ilé gbéwọn dé ta o, tọkọ taya kan sọnú bàálù di battle field lásìkò tí bàálù náà wà lórí òfurufú ìjà náà kọjá bẹ ni bàálù bá wá ibi bà sí kí wọ́n o ma ko ti wọn bá àwọn èrò inú balu náà.😂😂
©OmoArogeTv
Never forget the people who held your hands when nobody wanted to touch you.
Jumaat mubaraq to u all, we pray for more of it.
©Omo Aroge.
Never underestimate the power you have to take your life in a new direction, 'mon tolabal uula sehiira layaal" What's your intensions towards your neighbours success??? OMO AROGE NIWON BOROKINI
Kilode ti oo le taku t'olohun lorun,ki olohun waa lo le awon alaanu waa bae.
instead ti o fi maa lo ba olowo ti yoo maa gbe e si ....is coming.....
Olohun sun moe bii ishan orun e.
Olohun oo, gbogbo ibi ti alaanu mi wa lorigun mereerin agbaye, bami fi oro mi rinwon leti. Aamin🙏🙏🙏
©Agbara adura.
E sora funwon.
Awon Alfa irole Aye, awon woli eke.
E sora funwon, opolopo won ni won tidi eru awon Aje latara ijekuje.
E sora funwon, opolopo won ni won tinbe ninu ide awon Aje latara aini duro ti Olohun nikan soso.
E sora funwon, opolopo won ni won tidi iranse okuku latara Haram jije, ogogoro mimu ati awon nkan tiko tosi emi mimo bi kia ma je oga, asin, opolo, ori oka, ori ere, Ori aja, elede ati beebelo....kai Allahu Akbar.
E sora funwon, opolopo won ni awon emi Alujonu yio magbe Oro wafun latara awon ogun agbara buruku tiwon tilo nitori owo ati ije eeyan wipe kiwon ma so funyin nibiti won ba ti nye isewo funyin.
E sora funwon, nitoripe won o ni igbagbo ninu Al Qurani mo ooo, iro ni won pa mo esin Islam won o gba wipe oro olohun nikan leso awon di gbogbo nkan ti awon feda laye.
E sora funwon ooo, nitoripe won tigba abode latara ima ronu atunse arawon losi ibi 419 ati iba aye alaye je.
E sora funwon ooo, e sora gidi gidi nitoripe awon A*o nla nla, bata gidi, ago tuntun, fila original ni won fi nboju pelu tesuba.
E sora fun won, nitoripe Ara opolopo eyiti o je odo ninu won o bale nitoripe o nwa owo ojiji, o sife di Alfa Agba leekanna.
Kosi imole olohun ni arawon paapa.
E sora funwon.
©copied.
Kini mo je!
Kini moni!
Omo tani mi
Kilo fimi lokan bale!!!
Ti mio nii sin Olohun oba to se ipile isedaa mi.
Se bi tiwon ba nba e soo koo sin olohun, enikeni tiko ba sin olohun iya eleta elero nio je, to bawa nsope talo lo sorun to bo rii?
Sebi odo olohun to dae naa loopadasi lojokan, oo ranti ojo tiyoo kun iwo nikan ninu saare, k'olohun ma sewa ni adorun motito🤲
Atunbotan loju e ranti iku!!!
Ju gbogbo e lo, melomelo eni ton sinlohun lati ibere aye e tolojo fide, to waa padanu ijoba orun😪
Melomelo sini eniti kokirun ri, ko gbaawe ri, tosi bojuure olohun pade to waa rijoba orun😪 kabioosi🙌Olohun oba aseyi owuu.
Olohun joo, gbogbo igbiyanju mi loju ona esin mase jeko ja s'asan lojo ikehin, koo fi kelimot/gbolohun La ilaha iila Allahu لا إله إلا الله simi lenu lojo ikehin ati gbogbo eni ba s'amin adura.
©Omo Aroge niwon borokini.
A MESSAGE TO THE WHOLE WORLD Q5:V48
Surah Al-Maeda, Verse 48:
And We have revealed to you the Book with the truth, verifying what is before it of the Book and a guardian over it, therefore judge between them by what Allah has revealed, and do not follow their low desires (to turn away) from the truth that has come to you; for every one of you did We appoint a law and a way, and IF ALLAH HAD PLEASED HE WOULD HAVE MADE YOU (ALL) A SINGLE PEOPLE, but that He might try you in what He gave you, therefore strive with one another to hasten to virtuous deeds; to Allah is your return, of all (of you), so He will let you know that in which you differed.
A message to the world.
GBOGBO MUSULUMI AGBAYE
GBOGBO CHRISTIAN AGBAYE
GBOGBO ONISESE AGBAYE
E sunmobi e waagbo oro olohun, kilole maafa ija eleyameya esin, se o mope Olohun lagbara ko se gbogbo aye l'elesin kan naa sugbon, o wuu lo se see ni eleyameya. E kiye sii bi olohun ba fun wani anfaani lati mo ashiri ara re, nse ni ao maa wadie lojoojumo aye, idi niyii tofi jepe an baraawa ja toripe enikan kole ridi olohun mi Oba alekeola.
Esin temi komaa je ti, ki tie naa ma je tie!!! Sugbon iwo ti o ba duro loriipe Ogun esin, ija esin, epe tabi egun lori esin lo fee maa se lojoojumo aye, esin yoowu komaase, ranti pe KOSI IDILE TI AMAA DE TI AO NII BA METEETA NIBE PAPAA JULO NI ILE YORUBA TI AWA YII. Booba je musulumi ton sepe tabi gegun fun awon elesin tokun ranti pe ipile idile re tabi aromodomo re maa je nibe.
Bakannaa boobaje christian tonsepe fun musulum
Happy mood
Happy birthday to Omo AROGE in areas
Tomorrow for me Omo aroge in addy
Alhamdulillah for the successful of Ramadan and Eidul fitri 🙌
Death is the only surest door that every soul will enter
Do good for your own sake
Complement of the season I pray for
Good morning everyone, may this morning rain bring bright blessing to all of us in the mighty name of Allah. Have a blessed day ahead 👉