ADEX AUTO

FAMILY AND FRIENDS PLEASE LET ME
GET 50K FOLLOWERS

20/04/2024

THE MARRIAGE COUNSELOR.

TOPIC:- AKOKO{ Time}

Lara ohun tose pataki ninu igbeyawo ti o sefi owo ro seyin ni akoko wa, Ose pataki ki tokotaya ni akoko fun ara won, Yoruba ni ogiri toba la enu, Oun ni alangba ma n wole si, Bakanna natun sope ohun taba fi sile bai ni enu ewure ma n to, Kosi iro ninu awon owe mejeji yi, Awon okunrin miran tida igbeyawo ara won ru, Nitori aini akoko fun iyawo ati omo won, Awon obinrin miran na tida igbeyawo ara won ru, Nitori aini akoko fun oko won ati omo.

Lotito, o dara kase ise, Tori ise lafi n tan ise{poverty} Ise ni kije ki ebi pani, Sugbon ise taba n se, Debipe a o raye ti ebi wa mo, Afi ise saaa, Iyen o kise ise gidi, Oto ni aye ise, Oto ni aye fun ebi re, Nini akoko fun ara eni se pataki ninu igbeyawo, Aini akoko fun ara eni leda igbeyawo ru, Toripe okunrin miran o ni akoko fun iyawo ile re, Ohun ni iyawo sedi eni to n ni orekunrin nita, Toripe obinrin miran na o ni akoko fun oko ile re, Ni oko sedi eni to n ni orebinrin nita, Kosi aye ere, kosi aye awada, Kosi aye iba ara eni soro, Kosi aye fun igba ara eni lamoran.

Iwo toje oko wa laye, Oti ku, Sugbon ale ni iyawo re lo n fi oro lo nita, Ale lo n gba iyawo re lamoran, Nigba ti iyawo o ri oju iwo toje oko ile re nile, Kosi ani-ani, Oti wa useless ninu life iyawo re niyen, Oun lose nfi oro lo okunrin miran nita towa useful ninu aye re
Owa ninu ile gege bi iyawo, Sugbon oko re o kiri oju re nile, Oni akoko fun oko re, Odo orebinrin nita ni oko re tima n bere fun imoran toba fese nkan, Awon obinrin miran ti e wa gan, awon o mo bi won se n gba oko lamoran, Kosi iru oro ti oko lefi lo won, Gbogbo oro ti won koju pe, Eyi teba tise na loda lo, Imoran ti won niyen, Toba tidi pe oko re tilo n gba imoran wa lodo obinrin miran nita, Ajepe owa useless ninu aye oko re niyen

Lotito, awon okunrin kan na wa tan ma n ri ara won bi ologbon, Ti won o kiri iyawo won bi eni toni lakaye tole fun won ni imoran gidi, Oku die kato fun iru awon okunrin be na, Lara purpose of marriage ni kajo ma damoran papo, Nipa bi ase ma gbe nkan rere se, ati lori awon omo tabi, Sugbon larin tokotaya ti o bati si eyi nibe, Oku die kato fun won, Toba tidi pe obinrin ti n lo gba imoran bose mato ile re lodo ale re okunrin nita, Abi okunrin lo n gba imoran bose mato ile re lodo ale re obinrin nita, Sesi ni ki iru igbeyawo be ma pada daru, Ayafi ti awon tan n gba imoran lowo won baje eniyan gidi loku

Kosi iru ise tole mase, O gbodo ni akoko fun ile re, Bi oba feki ile re daru, Nje eje mope tori ounje lasan ni okunrin miran sedi oniyawo meji, Nigba ti iyawo akofe re o ki raye ma dana ounje fun lasiko, Tori aiki gbele oko ni obinrin miran sedi eni to n yan ale, Ise travel ni oko re nse, Igba toba tun jaja wa sile, Koni duro nile koba iyawo ati awon omo re sere, Odo awon ore ni o tun ma toju bo kiri, Iyawo toti fi sile tipe, Ole ma basun ju ekan lo ti o tun fi pada si travel, Bi iru won bawa gbo pe iyawo won n yan ale, Won awa ko agidi bori bi fanu Igbo, Awon gangan nasi silekun aye yiyan sile fun iyawo won.

Okunrin n se ise travel, Iyen o sope koma ni time fun ebi re, Toba travel, ri daju pe oun pe ile lorekore, Igba toba si wa sile, Fi ara mo iyawo ati awon omo re dada, Nini akoko fun ara eni se pataki ninu igbeyawo, Igbeyawo ti o basi pe a n ni akoko fun ara eni nibe, Orisirisi nkan lole sele ninu iru igbeyawo be.

Otan lenu, Oku nikun, Ki olorun mafi eyi se akomo fun mi, Kosi mafi se akamo fun eyin na, Ki gbogbo wa jope fun ara wa... Amin
Aimo, Bi eba ni ibeere kan, Abi efe pari ija larin eyin ati oloolufe yin, Boya esi nfe itoju fun eyikeyi arun ara ni,

LAGBARA OLORUN, ILE WA O NI DARU... AMIN.

19/04/2024

*8 REASONS WHY WE SHOULD BUILD THE PEOPLE AROUND US*

*1. Nothing Makes Life Sweeter Than Making People Happy*

*2. The People You Help Today Become Your Soldiers In The Battle Of Life Tomorrow*

*3. To Invest In Properties Is Good But To Invest In People Is Far Far Better.*

*4. Try To Make Money, But Also Try To Make People Great.*

*5. Your Greatest Trophies Are The Tears You Wipe Away From People's Faces Not The Wealth You Acquired.*

*6. Your Greatest Achievement Should Be A Way Of Raising People To Become Achievers.*

*7. People Will Defend, Honour You & Stand By You When They Realise You Value Them*

*8. Don't Let Any one Stop You From Making Others Great.*

*(Better to light a candle than to cause the darkness)*
Everyone

14/04/2024
29/03/2024

Chaiii thief is very bad

20/03/2024

*"BE CAREFUL With A FRIEND LIKE THIS:*

*1 someone who always want to have what you have by all means.*

*2 someone who is always competing with you.*

*3 someone who is not happy with your success.*

*4 someone who tell others lies about you.*

*5 someone who can not defend you behind your back.*

*6 someone who celebrates your failures and tears 😭.*

*7 someone who can't confidently trust you*

*Always observe your surroundings, identify them, mark them, operate with them from a distance. Many are no longer honest again."*

_*Happy Best Friend's Day*_

17/03/2024

A woman in Yola Adamawa State took her husband's Phone and checked his Facebook activities; she saw romantic chats with women. She sat down and thought of a way to separate him from the women. She came up with a beautiful idea, without even the husband's knowledge. She came up with the following methods

1- She copied all his chats with one of the women.

2- She opened a new Facebook account with a Male name.

3- She sent a friend request to the husband, he accepted the request.

4 - She introduced herself to him. She said "I'm Abu Dar'daee by name, a Member of BOKO HARAM. I saw all your chats with my wife. I want to warn you to stay away from her if you really want to remain alive. To clear any element of doubt, I have all the chats with me and here they are, you can see.

5- So, if you don't stop chatting with my wife, I'll slaughter you like Ram.
6- I know you. I know your name is Jamilu, your father's name is Mohammed, your mother's name Khadija, you have 3 children. Al'ameen, Zahara and Yusuf. Abdulrahman is your best friend and Usman is your neighbor. You are a Lecturer working at FCE. You also go to work 9:30am with your friend Usman, you follow Jambutu street and you spend time together. I'm warning you if you dare call, text or chat with my wife again, I will slaughter you like a Ram as I said earlier".

The wife was close to him while he read the message. As he was reading it, he kept sniffing and repeating Innalillahi WA innaillaihirraji'un. She asked him what happened, he said nothing. He immediately deleted his Facebook and Whatsapp apps and every other social media app.

The following morning, he went and sold the phone in the market and bought an ordinary Nokia. He told his wife to always wake him when ever it's time for prayers.

The woman said since that day, her husband has been observing prayers regularly and spending more time with the family.

Isn't that better than settling the matter with a knife?

HAVE A WONDERFUL DAY

14/03/2024

No be say marriage no de hungry me, na dese tin I dey try Avoide, I wan marry I wan marry ,na so I go de inside my Room de look Una Adebisi Williams

13/03/2024

BURDENED by the guilt over CIRCUMSTANCE beyond your CONTROL?!

Learn to MOVE on without feeling GUILT. Don’t let your good heart make you feel GUILTY on what you NEVER caused. Everyone
Please let me get 50k followers 🙏🙏🙏🙏🙏🙏

13/03/2024

BURDENED by the guilt over CIRCUMSTANCE beyond your CONTROL?!

Learn to MOVE on without feeling GUILT. Don’t let your good heart make you feel GUILTY on what you NEVER caused.
Everyone

Photos from ADEX AUTO's post 11/03/2024
05/03/2024

At this age, I want stability and peace
No lies, No games, and No cheating No insult No abuse
I got betrayed while my heart is pure, I
will never forget that....
I just keep praying for a relationship
full of trust, assurance and consistency.
Someone who can- match my Sincerity and love

04/03/2024

On the night of December 20, 1987, a Philippine passenger ferry, MV Doña Paz, collided with an oil tanker, MT Vector. Both vessels ignited swiftly, trapping passengers and crews in a devastating fire.

Among 4,385 people, only 26 survived the disaster. The survivors were forced to jump off the ship and swim among charred bodies in flaming waters around the ship, with some using suitcases as makeshift flotation devices.

It reportedly took eight hours before Philippine maritime authorities learned of the accident, and another eight hours to initiate search-and-rescue operations.

The tragedy stands as the deadliest peacetime maritime disaster in history.

02/03/2024

I want use this opportunity to thank you all for making my day a great one thank you all for your call text messages and Prayers may GOD almightybless you all abundantly
Thank you all once again celebrating Adebisi Williams BIRTHDAY

Photos from ADEX AUTO's post 01/03/2024

Happy birthday to Adebisi Williams may GOD almighty bless my new age

Otunba Adebisi Williams (@adexdray08) on Threads 26/02/2024

Otunba Adebisi Williams (@adexdray08) on Threads A MAN NO ONE I MEAN NO ONE CAN BUSH*T ME. 43 Followers.

17/02/2024
Photos from ADEX AUTO's post 12/02/2024

IT'S A BRAND NEW WEEK LET'S TALK MORE ABOUT BUSINESS 💯
ANY DISCUSSION APART FROM BUSINESS ❌❌❌
PLEASE FOLLOW MY PAGE AADEX AUTOGOD WILL BLESS YOU ALL

04/02/2024

Pure water dancing show

26/01/2024

THIS IS WHERE IT ALL STARTED

22/01/2024

HAPPY NEW WEEK MAY GOD ALMIGHTY BLESS THE WEEK FOR US

21/01/2024

ÌFORÍJÌN 2

Ìyàlẹ́nu ni ó jẹ́ fún àwọn akẹgbẹ́ Adéoyè ní ilé ìwòsàn láti tún rí i, Dokita Jìmí tí ó jẹ́ ọlọ́rọ̀ rẹ̀ sún mọ́ ọn, àwọn yòókù juwọ́ kí i bí wọ́n ti ń lọ sí àwọn yàrá aláìsàn tí wọ́n ti fẹ́ ṣiṣẹ́. Jìmí sún mọ́ Adéoyè láti bá a ṣe àwàdà, àmọ́ bí ó ti rí iná ojú rẹ̀, ó kára ro. Ẹnìkan kì í pé ohun tí ò ṣeni rí tún dé, Jìmí kò rí Adéoyè báyìí rí láti bí i ọdún mẹ́wàá tí wọ́n ti jọ ń bọ̀, wọ́n jọ lo ọdún mẹta ní ìlú Òyìnbó ni kí wọn ó tún tó jọ ríṣẹ́ sí ilé ìwòsan Ẹ̀míjàjù ní ọdún méje sẹ́yìn. Púpọ̀ àwọn ènìyàn ni wọ́n máa ń rò pé ìbejì ni wọ́n, nítorí pé bí i ọ̀rọ̀ ìgbín àti ìkarahun ni ọ̀rọ̀ wọn.
Jìmí mọ̀ pé ohun tí ó sọ ọ̀rẹ́ òun di olójú iná kì í ṣe ọ̀rọ̀ ìta gbangba. Ó fọwọ́ gẹ ọ̀rẹ́ rẹ̀ wọlé sí ọ́ọ́fíìsì tirẹ̀. Ó fi ìdí rẹ̀ lé àga, ó fọwọ́ mú un léjìká, ó sì wo ẹyinjú rẹ̀. Ó wí pé, Adéoyè kí ló ṣẹlẹ̀?
Dípò kí ọ̀rọ̀ ó jáde lẹ́nu Adéoyè ẹkún ló bú sí gbaragada. Jìmí fà á dìde, ó so mọ́ ọn bí ẹyìn ti í so mọ́ sọsọ. Ó wí pé, kò sí ohun tí ó fẹ́ ṣẹlẹ̀ láyé yìí tí ó jẹ́ tuntun mọ́, gbogbo ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ lásìkò yìí ló ti ṣẹlẹ̀ rí. Ṣé èèyàn kú ni? Ṣé o fi ọkọ̀ gbáàyàn ni àbí o fi pààyàn? O ṣi abẹ́rẹ́ gún ni àbí o ṣi òògùn fún-ùnyàn? Adéoyè tiraka dáhùn pé, gbogbo ohun tí ò ń bi mí yìí kọ́ ló ṣẹlẹ̀. Mo ti délé kí n tó padà. Jìmí wo ojú ọ̀rẹ́, Ṣé ilé ni nǹkan ti ṣẹlẹ̀ ? Adéoyè fi orí dáhun pé bẹ́ẹ̀ni. Ṣé ẹ lálejò ni? Ó tún fi orí dáhùn pé bẹ́ẹ̀ni. Jìmí wá bi í pé, kí ló ṣẹlẹ̀ nílé? Gbagada ni Adéoyè tún bú sẹ́kún.....

Kí lẹ̀yin rò pé ó ṣẹlẹ̀ tí ó fi wúwo lẹ́nu Adéoyè?
Wọ́n ní, akọ igi kì í ṣoje, kí ló sọ akọ igi Adéoyè di abo.

A ó tùn-ún máa tẹ̀síwájú ní ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀. Ire o!

20/01/2024

HAPPY BIRTHDAY King Tunde Ednut News

18/01/2024

*Appreciate the fake people in your life too.*

*Without them you won't have sense*

18/01/2024

*When you Get Married Make Sure your Husband Changes The Foam Before you Start Calling It Matrimonial Bed, E Get Why

18/01/2024

*I am sorry if you like me and i'm ignoring you. Me*
*self, person wey I like dey ignore me.*

*We are all "IGNORÅNCE

18/01/2024

*Lack of "I am sorry" has destroyed many relationships and marriage. Learn to apologize when You're wrong, it cost nothing.

18/01/2024

*You cannot be good enough for everybody, but you will always be the best for the one who deserves you.

18/01/2024

*If u want to no the true meaning of communication, then u promise a woman money, she will be like, darling have u eating tomorrow.

18/01/2024

*A wise woman doesn't ask for money from her man,,her character puts are in the man's budget 💯

Want your public figure to be the top-listed Public Figure in Lagos?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Videos (show all)

Chaiii thief is very bad
BURDENED by the guilt over CIRCUMSTANCE beyond your CONTROL?!Learn to MOVE on without feeling GUILT. Don’t let your good...
BURDENED by the guilt over CIRCUMSTANCE beyond your CONTROL?!Learn to MOVE on without feeling GUILT. Don’t let your good...
At this age, I want stability and peaceNo lies, No games, and No cheating No insult  No abuse I got betrayed while my he...
People can find rest in unexpected places. Drivers should always look around ALL their tyres before driving off.  Which ...

Category

Telephone

Website

Address


NUMBER 1 COLE Street
Lagos
Other Entrepreneurs in Lagos (show all)
JIM TIMMY NIG LTD JIM TIMMY NIG LTD
17, Ishaga Road, Surulere
Lagos

Jim Timmy Nigeria Limited!!!

Yemi Omobolanle ceo DodaVelva Stores Yemi Omobolanle ceo DodaVelva Stores
Lagos, 2341

Sales, Marketing, Entertainment

Richard Oluseye Anthony - Roluseye Richard Oluseye Anthony - Roluseye
Lagos, 23401

Richard Oluseye is a young Nigerian entrepreneur, a Philantropist in the making, C.D of Glitz Plus E

Mcjessiey Mcjessiey
Lagos

Official Page for Jesse Mcjessiey Aimuan | Drip King

Iyke Phelim Official Iyke Phelim Official
Lagos

Movie Producer, Music Producer, Media Consultant

Kaffy Kaffy
Lagos

This Is My Official Page. Guinness World Records Holder. Human Excellence Advocate . Mother . Coach

$H£GO DA PARTY PLANNER $H£GO DA PARTY PLANNER
111 Allen Avenue , Ikeja
Lagos, 023401

All about what's going on generally,what people are going through. Advices AND Help each other grow.

BLACK FAB BLACK FAB
Lagos
Lagos

https://dvpper.lnk.to/ukpokpu Entrepreneur Recording Artiste CEO Sound Yard🎧

Imaginations School Imaginations School
3, Association Avenue, Ilupeju
Lagos

Imaginations School is an offshoot of Imaginations Playstation. It started as a Creche/Playgroup in October 2006 but has now transformed into a school. Imaginations School comprise...

Liz Harrison Liz Harrison
Abuja-109Plaza Adetokunbo Ademola Cresent Wuse2 By Immaculate Hotel
Lagos, ABUJA,

ib_shoenique ib_shoenique
Ajah
Lagos

Your luxury personal shopper.At ib_shoenique we sell luxury branded bags and quality shoes at affordable price.

Everything_jgold Everything_jgold
Lagos

For all kinds of Strictly New Italian Gold Jewelry , We are Very Reliable , Tested and Trusted � ?