Obaerialasepe prayers link

Obaerialasepe prayers link

Religion organizations

03/01/2023

Oluwa loun fe tu enia 70 sile ninu oko igbekun ojo pipe pelu igbagbo re loruko Jésù oni bawon lo ogo re ninu iboji whatsapp me on 09060694087 odun 2023 tio wo Yi odun iselogo re ni odun esan sini pelu Mafi igbagbo re di ola Iwo tio wa igbe igbelu , visa, promotion, oko, Aya, ESO , ifokanbale Nile oko Whatsapp number 09060694087

03/01/2023

Bí ojúmọ́ bá mọ́, ọ̀ọ̀yè̩ á là péré gédé, ò̩nà kìí dí mó̩ o̩kó̩, ò̩nà kìí dí mo àdá, kósí kékéré ìgbìń 🐌 tí kìń ní ìlé lòrí. Gbògbó ádáwolé re má yorí sí réré,
ọ̀nà áséyorí má lá fùń è̩ lose yí. Loruko Jésú Kristi 🙏 call or whatsapp on 09060694087

03/01/2023

Join me on my TikTok user page that where we do our live everyday meet ur God and you shall be loose from bo***ge All ur case d lord will settle it and you shall share testimony

03/01/2023

Mopalase sinu aiye re bi ose wo Inu odun tuntun gbogbo ogo tio ti Sonu ni 2022 olorun yonda e fun e ni 2023🙏🙏🙏🙏

28/10/2022

God of obaerialasepe ❤️❤️❤️

28/10/2022
28/09/2022

IRAWO OMI...
Irawo Omi lagbara pupo, asasi ki Saba jaa won, sugbon egun idile baba nsaba maa nba won jaa pupo, ewe ati egbo ki sise lara won rara, irawo Omi ni obinrin iru won ni won ki gbe ile oko, won ki gbe ile oko toripe okunrin maa ngbe won ju sile ni, won a maa ni ewe pupo sugbon ogun promise and fail maa po fun won pupo, okunrin won nfie si ki won maa yan ale pupo...
IKOLO FUN IRAWO OMI.
🧜🧜🧜🧜🧜🧜🧜🧜🧜🧜...
Irawo Omi gbodo teramo awon unkan isori pupo lati ibere pepe aiye won, okunrin won gbodo sora fun isekuise toripe obinrin maa nda irin ajo won ru pupo toripe won nma nife si ale yiyan...
ISE IRAWO OMI....
Die ninu ohun ti irawo Omi le maa se.
NAVEY.
TITA EJA TUTU.
DOCTOR.
NURSE.
SEAMAN.
PURE WATERS.
FISHERMAN.
SWIMMING ETC.
Gbogbo ohun ti o baa jomo ise Omi...

27/09/2022

I pray that demon sending children to early grave, will not locate you and any of your children in Jesus name. Amen

27/09/2022

Oluwa loun fe tu enia 70 sile ninu oko igbekun ojo pipe pelu igbagbo re loruko Jésù oni bawon lo ogo re ninu iboji whatsapp me on 09060694087

27/09/2022

Gbo tobaleri amin nla kan se loruko Jésù oni bawon lo ogo iboji 🔥🔥🔥 fun iwo toun wa ise , oko, iyawo, iwe igbelu loruko Jésù loranugba call or whatsapp on 09060694087

16/09/2022

Mo soro ase ipe itusile sinu aiye gbogbo okan tole ri mi wo la saleyi mio iru ogun tio la koja tabi ogun tomu e sun ekun kikoro iwo toun wa oko rere iyawo , promotion, ise,visa, iwe igbelu oluwa se tan lati gba o LA loruko Jésù otun seeru aiye mo call or whatsapp on 09060694087

16/09/2022

Oluwa ni kin sofun eniyan 101 tole fi igbagbo pe fun itusile talo dajo toloun kajo awon ologo inu idile loruko Jésù kiwon gbina sonu call or whatsapp on 09060694087

16/09/2022

Gbo toba leri amin meje se ajo tiwon fi awon ologo idile da ti kije kiwon se rere loruko Jésù orun tu o sile oluwa ranmi si eniyan 61 lasaleyi ti aye ti fi ogo re sofo pelu igbagbo message or call on whatsapp number 09060694087

04/09/2022

Afternoon my fans both on my wall and page Obaerialasepe prayers link and Woli Idunu Eledumare fans join us on our live vigil program has you join us both my fan home and abroad you shall be favoured ijmn 🙏 cheers

12am

03/09/2022

Join us on our 3days live vigil starting 12am in d midnight join us and be delivered ijmn 🙏

03/09/2022

This is a vision coming I don't know if u have d faith God is releasing 71 visa, passports and documents oluwa ni ohun fe tu documents at visa enia 71 kale pls only those with strong faith should whatsapp me for d complete prophency whatsapp number 09060694087 heaven will speak for u ijmn 🙏

03/09/2022

Ni Oruko Jesu ni mo gbadura fun yin ni owuro yi wipe : ki Olorun yara gba yin, ki Oluwa yara lati ran yin lowo, ki Oju ki o ti awon ti nwa okan yin, ki nwon ki o si damu :ki nwon ki o si pada sehin, ki a si damu awon ti nwa ifarapa yin, NI ORUKO JESU🔥🙏🔥 call or whatsapp 09060694087

03/09/2022

Who Is online....?

I saw a visa and passport and documents, but I don't know the Owner if you are believing in God for that, receive it now, in Jesus name🔥🙏🔥start calling or whatsapp 09060694087

03/09/2022

I pray that curse on your hand not to touch good money is broken now in Jesus name. Amen many setan has stop them from been wealth there is a secret to be financial stable d lord gave me start calling or whatsapp on 09060694087

02/09/2022

Toba leri amin nla kan se alagbara todi ona mo o orun ja okun emi re.....oluwa ranmi si enia mewa pere oluwa ni kin fi ase oro tu yin sile fun eni toba ni igbagbo bere si pemi lori whatsapp 09060694087

02/09/2022

Loruko Jésù oni bawon fi iku lokiki laiye oni bawon lo ogo iboji lase edumare 🙏🔥🔥🙏 fi adurayi sowon si enia meje, call or whatsapp on 09060694087

02/09/2022

First 50 luckiest people should inbox me for prayers and prophencie the lord want to deliver you from bo***ge of setan that is bringing stagnation in ur lives call or whatsapp on 09060694087

02/09/2022

Oluwa ni kin gbadura fun enia 102 laroyi nitori awon ti aye ti fi won sinu igbekun ogun kan tabi ikeji loruko Jésù pelu ase oro to sakale leni lori itusile gba🔥🙏🔥

02/09/2022

Gbo Oluwa ni ki gba adura yi fun Okan to gbagbo, gbogbo A*o Egun Iran, ti aye wo si emi ati yin lorun, emi mimo Olorun alaye fi ina bo danu,
Majemu ipinle ti a fi ba aye wa jagun, loni majemu na baje,
A*O iponju ti aye fi ta wa lore, loni emi mimo fi na faya,
Gbogbo ina Ogun lara temi ati yin, Loni oluwa fi omi Anu pa,
NI ORUKO JESU.......fun enia ogoji 40 tofe ri itusile gba bere si ni message mi lori whatsapp 09060694087 olorun fe tu yin sile 🔥🙏🔥

01/09/2022

Ninu osu tuntun yi, E lo ri anu Ati ojurere pelu iranlowo atokewa gba loruko jesu amin.

31/08/2022

Bíbélí Wípé 👉 Elijah gbádúrá fùń odùń mettá átí ósú mefá kí òjó má ro. Mó ló Áse Ìgbání sìńù Áyàńmo re pé. Áso átíjo, Ìlé átíjo, Òùńje átíjo, Ìgbé áiyé átíjo, Bátá átíjo, Ore átíjo tòfá ògùń átíjo síńù áiyé re. Ìnà 🔥 Oluwa jáwòń kúró láíyé re. Loruko Jésú Kristi 🙏🔥🙏

21/08/2022

Oluwa fi iran kan hanmi wipe opolopo toun seru labe ogo won tosi wa iwe igbelu oluwa ni ohun se tan lati ju awon 55 enia kan , for has many that have been slavery under there glory many that is crying for there documents and promotion outside d country d lord said is ready to loose 55people within three days with there faith call or whatsapp number 09060694087

Photos from Obaerialasepe prayers link's post 20/08/2022

Afternoon my people happy weekend tomorrow is our children aniversary thanksgiving please we will appreciate people donations toward d children to get different types of fruits for them........I pray for every hands that bless our children wealth shall serve u all ijmn 🙏

Photos from Obaerialasepe prayers link's post 20/08/2022

Mopalase gege bi woli fun ologo eniyan 20 tole ra eso fun ori oke yi fun awon omo wewe wa loruko Jésù ogo ajemonu koje tiyin eeto tie tiun reti yen loruko Jésù olorun kofi iseda awon omo wewe yen kofi silekun ayo fun yin! Call or whatsapp 09060694087

20/08/2022

TOPIC :ATUNSE SI NINU IJO OLUWA :KILODE TI E BA A*O ADURA JE BAYI EYIN OMO KERUBU, BI E BA MA RAN WHITE KI E RAN WHITE, BI E BA MA RAN BLUE E RAN BLUE, BI E BA MA RAN YELLOW E RAN YELLOW,O SE NI LANU WIPE OPOLOPO ENIYAN LO SE MIX UP, A*O ADURA NI KI SE A*O ILE, SE EYIN KO MO WIPE ANGELI AMULUMALA WA NIYEN NI TI ESU, SE BI BABA WA MOSEORIMOLADE SE GBE KALE RE NI, AWON AGBA IRANSE OLUWA NA, TO YE KI O MA BA NI WI, KI WON MA TONI SI ONA OLUWA, TO YE KI A MA WO BI AWO KOSE RERE , AWON NA SE OHUN TO WUN WON,NITORI OWO WON LE SO OTITO ORO MO , OTITO ORO TI KU MO WON NINU BI EYIN ADIEYE, EYIN YOUTH
LE JE KI WON MA BU IJO ALA*O FUNFUN, IJO MIMO NI KERUBU LATI OKE WA, IJO ITUSILE NI, IJO IRAPADA NI PELU, ONI KALUKU WA SE A YI TO WUN WON SI ELEDA WON, EJO E JEKI AYI PADA SI OLORUN, NITORI IBINU OLORUN BO LORI AWON OMO ALAYIGBORAN,, E MA JE KI NINU OLORUN RU SI WA, E JE KI A SE BI WON TI SE, KI O LE RI BI A TI FE,EYIN AGBA KERUBU E SE ATUNSE SI NINU IJO, KI OLORUN LE GBO ADURA WA, NITORI AWA KI SE TI AYE YI, BI KI SE TI OLUWA, EJE KI A RONUPIWADA KI A LE RI ANU OLORUN GBA, IPE TI OLUWA BA PE E NI KO DURO LE LORI, KI OSI MA FI ADURA RAN IPE RE LOWO, YIO SI DARA FUN YIN, AGBARA LATI SE ATUNSE NINU IJO MIMO YI, OLORUN YIO GBE WO WA,

20/08/2022

AMIN NI KI E SE LOWURO YI, OLORE OJIJI ATI ALANU OJIJI, TO MA YI ITAN IGBESI AYE EYIN ATI IDILE YIN PADA SI RERE , NI WON BA TOKU KI ODUN YI PARI,KI E LO PADE RE PELU INA, NI ORUKO JESU,NIBI TI AIYE TI DI NA MO O LORI ANU GBA NIBE

19/08/2022

Gbo asotele lenu woli olorun alaye oluwa ni awon ogo kan ati fiwon se pasiparo fun iwo toleri Amin nla se loruko jesu onimajemu ko paro ogo re pada si rere! Oluwa ni ki ara bottle water, ororo koya onala and wall clock si ori ile anu fun 21days ko pa dandan fun awon toni igbagbo ni olorun ranmi si loruko Jésù oluwa ni ofe tu awon ogo kan sile ninu igbekun ogo toun se eeru call or whatsapp on 09060694087

19/08/2022

ORO LORI IBUJOKO FUN GBOGBO OBIRIN. ATI ONA ABAYO FUN ISE ANU NLA, LOVE ATTRACTION, ISE IBUKUN FUN GBOGBO ONISE OWO ATI ONLINE

Bi aba nso nipa ibujoko obirin, a nso nipa ile oko obirin. Obirin ti olorun bawa fun ni ibujoko ayo, to ri okurin gidi to mo iyi obirin fe loko, oye ki iru obirin be ma dupe lowo olorun ni, nitori opo obirin lo nwa iru anfani ti iwo ni, sugbon ti won o ni. Kosi obirin ti ko wu ko wa ni ile oko, kadara londamu awon miran , awon miran de wa to je wipe afowofa won ni. Ibujoko taye yato si kehinde sugbon opo obirin lon wa ibujoko ti ki se tiwon kiri.
Odo okurin ti ko ni owo lowo ni ni ibujoko obirin miran wa sugbon ama claim age ani ohun ole fe okurin ti oun ju lo, laimo wipe ati yan koni nkankan se pelu ojo ori.. Iyawo akofe anobi Muhammad (S.A.W), 15years logba lowo anobi kosi aburu ninu ki ofe eni to juo lo.
Ohun to se pataki ni ki oni ayo ati idunu ninu ibujoko re. Odo akanda eyan ni ibujoko obirin miran wa sugbon ani oun ole fe alabo ara. Bi eniyan bati siyan laaro ojo aye e irin ajo eyan ma nwo. Iwo ti olorun bawa fun ni ore ofe lati ri oko gidi fe, mawa tun fi ayo fo. Ma se jeje kosi ma gboro si okore lenu tori ibujoko ti iwo wa yen omije oju ati opolopo awe ati adura ni awon obirin kan fi nwa, bi iwo bawa ni ibujoko ayo, lore nla ni olorun se fun e. Toju ibujoko re koma ba padanu re..
Kosi obirin tio wu ko wa nile oko, bi iwo basi ko ti omo oko re lo won ma gba lowo re. Ri oko re gege bi alase re, iyi nla ati aponle ni ki obirin wa ni ile oko. Bi eba ri obirin toni oun o ri ti okurin ro, idunnu ati ayo ko lofi so.. Owu oun na kowa nile oko. Lagbara olorun eyin ti eri oko rere fe, ile yin oni daru o.

FUN ETO ADURA ATI ONA ABAYO LORI IBUJOKO,. ISE ITUSELE ATI ISEGUN LORI IBALOPO LOJU ORUN, TABI IWO TI OKO ATI AYA ORUN DA LAMU..LORI ATI RI OMO BI...ALAKALA...CALL OR WHATSAPP.. NUMBER 09060694087 FI ADURA RANSE SI GROUPS IYE TO WU YIN,..IBUJOKO RE KO DARU NIPA ASE OLORUN

Want your public figure to be the top-listed Public Figure in Osogbo?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Videos (show all)

Mo soro ase ipe itusile sinu aiye gbogbo okan tole ri mi wo la saleyi mio iru ogun tio la koja tabi ogun tomu e sun ekun...
Oluwa ni kin sofun eniyan 101 tole fi igbagbo pe fun itusile talo dajo toloun kajo awon ologo inu idile loruko Jésù kiwo...
Ninu osu tuntun yi, E lo ri anu Ati ojurere pelu iranlowo atokewa gba loruko jesu amin.
Oro iree itusile owuro edidi meje from prophetess idunu eledumare obaerialasepe call or whatsapp 09060694087
Loruko jesu lobo ninu igbekun aiye call or whatsapp on 09060694087
Share share share in 21 groups and d lord will deliver u from bondage🔥🙏 call or whatsapp 09060694087
Ase oro itusile meje from anointed mother obaerialasepe 🙏Call on 09060694087 or whatsappBless you ijmn 🙏
Isorun asegun
Loruko jesu irin ajo malaika yi atu gbogbo wa lara o onimajemu ni ofe si gbogbo ilekun ayo ti ati kale🙏🙏🙏Contact obaeria...

Category

Telephone

Website

Address


Agunbelewo
Osogbo