YORUBA DUN NI ASA

Asa wa,ise wa ni ile yoruba ko gbodo parun,ojuse gbogbo wa ni,e jeki a gbe laruge!

18/05/2024

Ojumọ ire loni ooooo🙏🙏🙏🙏🙏

06/05/2024

Akoba , adaba, Edumare ma jẹ kí a rí. Ẹjọ elejo, ọrọ ọlọrọ Oluwa ma jẹ kí o di ti wa OOO

05/05/2024

Ewo nínu yin lo tà omi ni 2500 fún maami Fali werepe 😂😂😂😂😂

05/05/2024

A ku Ojumo OOO, e ba wa dá sí ọrọ to nlọ lọwọlọwọ bayi, Ṣe ọjọ orí nise pẹlú igbeyawo?

01/05/2024

Hmmmmmmmmmm

29/04/2024

Orí mi a jí ki, Ori mi a jí gẹ, iwonran Olokun a bí àrà Le koko bi ọta, Ori mi timileyin, Iseda mi ma gba Abode, ìbí orí mi yíò ti sunwọn ju ibi ti mo wà yi lọ, ẹsẹ mi ma ṣe alaigbe mi fe ibè àti gbogbo ololufe Yoruba dun ni àṣà pátápátá. Ọsẹ yi a san wa opópo🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏

27/04/2024

O dìgbà o SE Egbin Orun fi ayé silẹ lọ 😭😭😭😭😭😭

26/04/2024

Alhaji Ganiyu Oyeyemi Ogunjinmi Àjàgà jigi Oògùn o di gbere,o di Arinnako, sún ré Oooo😭😭😭😭😭😭😭😭😭😭

25/04/2024
25/04/2024

E ku Ojumo Oooo, follow for follow

05/04/2024

Ile Ariwo🤣🤣🤣🤣🤣🤣

01/04/2024

Bi a Se fẹ ló ma ri lasẹ Edumare 🙏🙏🙏🙏

31/03/2024

A ku ewu Ọdun Àjínde, èmí wa a se ọpọlọpọ rẹ̀ láyé lasẹ Edumare

30/03/2024

🤣🤣🤣🤣🤣🤣

30/03/2024

Portable ọmọ ologo,ku oriire o. Ayọ ti wa naa ma De lasẹ Edumare

30/03/2024

Eleyi tun peleke Oooo, awa na ni igunnuko Oooo🙄🙄🙄🙄🙄

30/03/2024

E ku ojumọ óò, gbogbo ọmọ Kaaro o jiire, kinni ẹyin naa Ri sọ sí ọrọ to nlọ láàrin jigan ati Dayọ Amusa, ọpọlọpọ eniyan nsọ wipe arifin ni kì jigan ma ṣọ ọrọ kobakungbe sí Dayo. Kínní èrò ti'yin?

27/03/2024

Tani yi o parí ìjà yì ooooo🙆🙆🙆🙆

27/03/2024

Lori Portable ati bobrisky oluwa gba ọpẹ wa

09/02/2024

Arin takiti😂😂😂😂😂😂

06/01/2024

Ibo la tun jà sí oooo

05/01/2024

Gbogbo wa la jẹ gbese ikú, Edumare jẹ kí ọdun jìnnà sira wọn.

04/01/2024

O di gbéré, o di Arinnako, o tún di oju Alá, Ọlọrun ba wa fi òrùn ke Bàbá Olofa iná. Bàbá fi Aye silẹ ni ọmọ ọdún metalelaadorin

17/10/2023

Hmmmmmmm

13/10/2023

Ayọ a bi ara tinntin Davido ati Chioma ku oriire Ìbejì lanti lanti

10/10/2023

Baba iyawo è se sùúrù oooo

10/10/2023

Orisa ni Obinrin e ma wadi Obinrin

04/10/2023

Epe nitori A*o party, Èèmọ!!!!

Want your public figure to be the top-listed Public Figure in Osogbo?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Videos (show all)

Akoba , adaba, Edumare ma jẹ kí a rí. Ẹjọ elejo, ọrọ ọlọrọ Oluwa ma jẹ kí o di ti wa OOO
Ewo ninu yin lo tà omi fún maami Fali werepe ni 2500
Ewo nínu yin lo tà omi ni 2500 fún maami Fali werepe 😂😂😂😂😂
Ọjọ orí Abi ifọkanbalẹ? Ewo lo se pataki
A ku Ojumo OOO, e ba wa dá sí ọrọ to nlọ lọwọlọwọ bayi, Ṣe ọjọ orí nise pẹlú igbeyawo?
Hmmmmmmm
Hmmmmmmmmmm
Orí mi a jí ki, Ori mi a jí gẹ, iwonran Olokun a bí àrà Le koko bi ọta, Ori mi timileyin, Iseda mi ma gba Abode, ìbí orí...
https://www.facebook.com/profile.php?id=100057874406109&mibextid=JRoKGi
Ile Ariwo🤣🤣🤣🤣🤣🤣
Orisirisi asa lo wa laye
Eleyi tun peleke Oooo, awa na ni igunnuko Oooo🙄🙄🙄🙄🙄

Telephone

Website

Address


Opposite Government House Annex, Oke Fia
Osogbo
234035

Other Osogbo public figures (show all)
Osun Osogbo Festival Osun Osogbo Festival
Osogbo

OSUN OSOGBO FESTIVAL 2011 Start August - 26 Iwopopo (cleansing of road) holds on August 15 Light

Nexus Multimedia Nexus Multimedia
Suite 13 Capital Gateway Plaza, Kugbaru Road
Osogbo, 234

Nexus Multimedia Solutions is a total solution provider for webhosting solution, multimedia solution

Amb Tunjikrown and the Melody Reloaders Amb Tunjikrown and the Melody Reloaders
Osogbo

music is our life....and we do it for the pleasure of our clients....

thrifshoekd thrifshoekd
Temidire
Osogbo

Saoty Arewa Fans Club Oshogbo Saoty Arewa Fans Club Oshogbo
Agowande Area
Osogbo

Saoty arewa fans club Oshogbo

Ijoba kuti Ijoba kuti
Simmering
Osogbo, 080614

My name is ijoba kuti,am a comedian boy if you want more about me on WhatsApp 08061439212,

Woli Yemight Dance Drama Ministry Woli Yemight Dance Drama Ministry
Osogbo

Producer,Actor, Director, script writer, song composer, Radio presenter, comedian,and m.c

OMO IDUNU ABAKE Fans/club OMO IDUNU ABAKE Fans/club
Osogbo, OWODEILESHA

Hajia Maryam Abake OMO IDUNU IBUKUN OLOHUN I She is a good Islamic singer

Matthew Alabi Matthew Alabi
Osogbo

Invoking shifting and lifting of the spirit in the spirit for the spirit.

Habeeb comedy zone Habeeb comedy zone
Alhaji Adelu
Osogbo, 230001

Welcome, I am an experienced professional in this business.i have get to much research and I have know more about this job very well.if you want your music get promoted, kindly mes...

Dchords MUSIC Dchords MUSIC
No's 12line 3 Surulere Strt Powerline NEPA Second Gate
Osogbo

about music