Apase-Odu2

Apase-Odu2

Moshood akeem oyewale,a.k a gbemuyona

Photos from Anabi-Jollof,omo Odo-agba.'s post 25/04/2024
22/02/2024

•• Oríkì Oníkòyí••••••

Ẹ̀ṣọ́ Ìkòyí Ọmọ adìílẹ̀dogun,
Yánbínbólú ọmọ Oníkòyí Ẹ̀ṣọ́.
Sèbí ogun lódé
Lẹ̀ṣọ́ ń pe ara won lórúkọ.

Ẹ̀ṣọ́ Ìkòyí ò gbọfà lẹ́yìn rí, iwájú ni baba wọn fí i ń gbọta.
Ẹ̀ṣọ́ tó bá gbọfà lẹ́yìn,
Ojo ló ṣe nílé baba wọn.
Ẹ̀ṣọ́ Ìkòyí omọ ẹkùn ààyè,
Ẹ̀ṣọ́ọ Ìkòyí ọmọ Arógunb’ẹra bí asọ.
Ìkòyí esin rógunjó
Èyí tí ò gbọdọ̀ rí ikú sá.
Kíni ikú ó fìran Baba tó bí yín lọ́mọ ṣe?
Ẹ̀yin lọmọ iwin róungbé,
Tí wọn bá ńlo lọ́nà ilé Agberioga .
Agberioga, ọmọ ayoyun
Sèbí àwọn lọmọ pèsè dè mí ń o yà lábọ̀
Bóò sì rí mi mọ́, o gbe’se naa jẹ
Ẹ̀ṣọ́o Ìkòyí, Ọmọ ẹru ọfà
Yánbínbólú, ọmọ a yan pọ́nrán níwájú ogun.
O ta kaka gb’ariwo ogun woyowoyo
Ojú méjì ni ti were n jeje,
Dudu to ti mo’le,
Timo
Pupa ti mo’le,
timo
Àbàtì àlàpà tí ń ba ara rẹ̀ lẹ́rù.
Ogun à jà wẹ̀yìn ló ń m’Ẹ̀ṣọ́ wùn mí,
Ogun ojojúmọ́ ló mú ilé bá baba yín sú mi lọ.
Ọmọ Ẹ̀ṣọ́ Ìkòyí,
Ọmo ẹrú fisanfisan.
Ìkòyí Alake, ọmọ ẹrú ọfa
Ẹ̀ṣọ́o Ìkòyí kìí jòkété,
Igba fínfín ni wón fí ń se
Aya Oníkòyí ko gbọdọ̀ j’ẹga
Ọmọ Oníkòyí ko gbọdọ̀ jòkété
Aporógunjo Ìkòyí gbéra nílẹ̀ o dìde ogun tó lọ,
Eyin lọmọ asi’ju apo piri dagba ọfa sọ́fun.
P ọ́’fun yóò dagba ọfa sílẹ̀.
Ọmọ akú f’epo tẹlẹ koto,
Omo igúnnugún balè wón á jorí,
Àkàlàmàgbò balè wón á jẹ̀dọ̀
Ọjọ́ kínní t’Oníkòyí kú,
Oju mi páà lóṣe.
Àgbà ni mibkò tíì dà.
Sùgbón mo kúrò lọmọ àgbékọ́rùn lọ'nú oko.
Wón gbẹ́’lẹ̀ wọ́n bo Oníkòyí
Mo nípẹ̀kun òrìsà nlá
Àgbède gbédé Oníkòyí ló sun ibẹ̀
Àtàrí Oníkòyí kò sun ibè.

© Bámgbọ́pàá

Photos from Apase-Odu2's post 22/02/2024
Profile pictures 22/02/2024

Good morning

Profile pictures 27/09/2023
27/09/2023
02/01/2023

Moki gbgb eyin temi wipe akum odun,emin yii se pipo e re,emaa binu sini,oro ona lo gbgb baamiiloo,pemi bayi fun isoro kisoro toba doju koe lavo ara,yabi iwo fee se ade-oba,a*o-egungun,a*o-ooogun a*o ogun ibile,tabi o fee ki a bao to ile agbaraa re kole no oju,iwo ti oko re ko feran re no,iwoti iyawo re ti feedi iyawo oniyawo,yara kan sini o,08100593495 apase-odu2

10/02/2022

Happy Birthday to Fathia & Saheed Balogun

May God bless your new age💖🙏

Photos from Apase-Odu2's post 13/11/2021

OGUN TUDE-ASINA TODAJU
omo seereyo(omo-ayo)meta,ataare ajakan,sisee re;ao fi okun di omo-ayo meteeta papo,konii see fii,ao daa sinu agbada, pelu,ataare aja yen,ao joo,ao fi sin gbere yipo orun owo wa mejeeji,ao fii iyoku fokomu leekansoso, fenikan loleloo ,confirm

Photos from Apase-Odu2's post 27/10/2021

EYIN TEMI eje kaamaa lo use TUDE AROBI-ASINA YII ni ilaare,siseere;-
Tio oru baa bere sii rubo,ti owo pa,ti ese pa ti awa maa tisetan atisun,amaawaa by omi to towa fii sanra ,so gbe kale Nita gbangba, so daa eyo-atare3 senu, aowa gbe e enu sinu o.omi yen, ao maa pe gbolohun re, ,ofore;-epademi ni inbox

Sàlímọ́tù Kékeré | Yoruba Children’s Song | Nigerian Nursery Rhymes | ABD Yoruba 01/10/2021

Sàlímọ́tù Kékeré | Yoruba Children’s Song | Nigerian Nursery Rhymes | ABD Yoruba This Yoruba classic song is teaching the young ones the negative effects of disobedience. Sàlímọ́tù is a naughty child and will not listen to her parents. Th...

23/07/2020
04/05/2020
20/04/2020
30/01/2020
10/11/2017

Mokigbogbo Eyintemi Ten like Page Yi,eoni Rare Lola Anabi{.S.A.W},edakun Eje Ka Beere Oogun Lowo Arawa Abi Ise Kinlagba.

01/11/2017

Iriran Todaju,imuumuna 2,eyo Ataare 2,ao Lomo Lotooto,imumuna Kan Eyo Atare Kan,aolopo Gbere Kan Ni Ojukan,aotun Lo Ikeji Nabe ,ao Si Oun Naa Si Isale Eyin Oju Keji,lobatana.

15/10/2017

IBA OLOHUN IBA EEYAN,WAA KO DIDA IFA,TITE OPELE,PELU ENDINLOGUN,enito mona niito,ejekia fi asiri oogun han araawa,funmi kinfun,emaapuro emase'ke,emajale,ema post iro,eni toba niya niko degbo eyin o,pe OMO OBA ADEYINKA ADELEKE SORI AAGO YII,08131610039 beere oogun toba wuo ipa olohun maakaa.

15/10/2017

Apase-Odu2

Want your business to be the top-listed Business in Oyo?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Telephone

Website

Address


Atiba Townhall
Oyo