omo-ogbe spiritual healer

I
omo-ogbe aiyelala spiritual healer, we care for any kind of spiritual attacks or problems such as

23/12/2023

OGUN OSO INU TO DAA.
ORI EJO oka kan, ewe ajikawo tutu to po dada, paid at are kan ai Jo po a ma fi se

23/12/2023

We can recreate you to what you want

23/12/2023

Ogun ogu-oru tabu warapa to daju

08/10/2023

True/false?

1 year since... 01/10/2023

1 year since... 3 new items · Memory by deluma olasunkanmi

21/01/2023

Ògùn ijangbara fún 2023 elections

02/11/2022

ÒGÙN ALEKO

Ọpọlọpọ ewé biyenmen, ao bo èpo atare kúrò, ao Jo pelu ewe yen, ao ma la.
08022261089 WhatsApp

02/11/2022

ÒGÙN ISOYE

Ewe òjiji, ọkan àkùko adìe, iru, ìyèré ao lọ pọ, epo, iyọ ao wa fí se eja ojiji jẹ. Ẹni kan soso lo wa fun

02/11/2022

OGUN KI OYÚN MA LE BÀJÉ

kòròfo ẹyin adiẹ, ọkọ atare kan, ao lọpọ, obinrin náà yóò ma fi fokomu

02/11/2022

ASEJE TIA FI NSU ABILU, ÈPÈ ATI ỌFÀ DÀNÙ KÚRÒ LÁRA

Egbò isepe agbe,iye agbe, iye àlùkò ikoride, ọmọ atare merindinlogun, ìyèré, ao lọ wọn pọ, ao fí se eja arọ je,ao ṣe ní alé, ao jẹ ní arọ kùtùkùtù Lai sọrọ sí ẹni kankan, ao gbé dání jẹ nio.
Ofore:-
Gbogbo oun to nṣe mi, èpè,abilu, ọfà, mo ti yà dànù l'oni. Tori sísu ni agbe nsu oro, sísu ni àlùkò n su ofà, ẹnikẹ́ni ki di odidẹrẹ lọwọ níbi to gbé npo iko rẹ nilewo, ọmọ oyebeyebe. Ki ibi ma ṣe ba mi láti òní lọ. Gbogbo èpè àti abilu, oro ọfà to wà lára mi, mo ti yà dànù l'oni.
N.B. no s*x for 3 days
For more explanation WhatsApp me on 08022261089

02/11/2022

Awúre osó

Eyelé funfun kan, ao la ní àyà, ao fí orí ọka kan sí, orí èrè,kan sí, ao wa gbé sínú isasun tuntun, ao gbé sínú ibí kan, tio ba di ọjọ kẹsan, yíò tí yó idin to pọ, ao wa ko sínú odò, ao gun mo ọsẹ dúdú, ao wa ko pada sinu isaasun náà, ao ma bi wẹ

15/10/2022
07/10/2022

OFO RE:-
Babaguruho, babaguruho, baba arinoworoko difafun Baba arinataaradefe. Awon niwon sefa fun orunmila, lojo ti baba ji, ti baba o lokan a na, baba nbe laarin Ora. Akogunnugun de, o lohun o jowu, IFA ni won kii jowu, won bere si ni be orunmila, won ni ko gbe won de buna. Orunmila ni oun koni gbe won de buba.
Won lo doro imule Loni. Orunmila ni ki lohun imule naa. Won ni , koni korowu,koni atare, koni ikoride. Wonni enikeni tio ba DA lara re, awon koni Baja, awon koni ba ise re je tomotomo.
Wonni ojo kiro ko pana ikoride, o di oniyebeyebe ni tikoride.
O dori owiwi eye ajoru, oloun o jowu, IFA leye kii jowu, o ni beye ba jowu, eye a sun, IFA a pa.
O Dori awon iyami osoronga, won lawon o jowu, IFA ni beye na jowu, eye a sun, IFA a pa.
Emo L.O.L no ti di ohun eewo fun oso , aje,etc
El eye toba doju komi, nise ni ko sun, ki IFA pa.

So wipe mio ni rija awon agbalagba, kio ba me me fun o
08022261089

07/10/2022

ASINA TIPATIPA.

Isawuru kan, atare kan, epo obo, ao jo po. Ao ma fi omi gbigbona lo laro kutukutu ki orun to yo.
Ofo re, 09032357538

07/10/2022

AGADAGODO

ohun pepeye, ohun aguntan, ohun elede,panumo abo, panumo Iya,panumo abafe, aba, owu dudu ati funfun, owu etutu.
Too ba nice so, call 08022261089

07/10/2022

OGUN ASEGBE TO DAJU.

Abe oro to ti gba eje Dada, ewe gbegbe 201, hmm m call 09032357538

07/10/2022

EBE AWON AGBALAGBA .

Ewe iyalode fun fun 201, opolo ijoku, igba olomori, ose dudu. Ao gun ewe yen pelu ose kuna Dada. Ao wa mu opolo ooye yi sinu igba ao wa ko ose yii le Lori. Ao gbe pamo fun ojo meta. Lehin ojo keta ao ma fi we. O damiloju tiwon ba ti pin eran eniyan , won yio da pada.
So wipe aye ko ni binu sino
08022261089

07/10/2022

OGUN AWURE OLA.
Ise yi yara soni di olowo.

Ewe akisan, Ede pupa osa16, eyele fun fun1, ata ijosi

07/10/2022

OGUN AWURE OWO KIAKIA.

Ogun yi dabi igba ti a ba fi fertilizer si nkan ogbin, tio si gbera kiakia.
ASEJE OWO KIAKIA.
Ewe aje tutu, ewe sawerepepe tutu, eja Aro merin, iyere, ao lo awon ewe yen ati iyere, ao fi se awon eja yen je lepo niyo.
Ao so sori osuka a*o fun fun. Ao fi iyerosun te IFA irentegbe ao pe ofo re si. Ao wa je

Ofo re:- 08022261089

29/09/2022
29/09/2022

A young couple moved into a new house.

The next morning while they were eating breakfast, the young woman saw her neighbor hanging the washing outside.

"That laundry is not very clean; she doesn’t know how to wash correctly. Perhaps she needs better soap powder.

Her husband looked on, remaining silent.

Every time her neighbor hung her washing out to dry, the young woman made the same comments.

A month later, the woman was surprised to see a nice clean wash on the line and said to her husband, "Look, she’s finally learned how to wash correctly. I wonder who taught her this?"

The husband replied, "I got up early this morning and cleaned our windows."

And so it is with life… What we see when watching others depends on the clarity of the window through which we look.

So don’t be too quick to judge others, especially if your perspective of life is clouded by anger, jealousy, negativity or unfulfilled desires.

"Judging a person does not define who they are. It defines who you are." Love this!

29/09/2022

Asiri ona abayo

Want your business to be the top-listed Health & Beauty Business in Ikorodu?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Videos (show all)

Asiri ona abayo

Telephone

Website

Address


Ikorodu
10007

Other Alternative & Holistic Health in Ikorodu (show all)
Jigsimur Total Remedy Jigsimur Total Remedy
Ikorodu

"We sell the best award winning and curative herbal jigsimur herbal bitters and tea, made from 100% herbs and roots and free from chemicals for the effective treatment of various h...

Sbmbotanicalsupply Sbmbotanicalsupply
Lagos Road
Ikorodu

Nan Naturopathic Clinic Nan Naturopathic Clinic
2, Abolarinwa Avenue , Elepe, Lagos
Ikorodu

Nan Naturopathic Clinic focuses on holistic healing, using herbs, acupuncture, hijama and massage, and other natural therapies in treatment.

Chacha FOODS Chacha FOODS
Road 5, Idafa Olopon, Maya Ikorodu, Lagos
Ikorodu

I'm a Certified Biochemist. I can help you regain your holistic health using herbs, lifestyle changes. Let what you eat be your medicine 🔥 Go Organic....Go Natural 🔥

Ahl al-Bayt Qur'aanic Healing Ahl al-Bayt Qur'aanic Healing
1, Alh. Kamaldeen Mustapha Street, Off Kas Avenue, Behind Sabo Market, Sabo, Lag
Ikorodu, 104101

We specialise in providing treatment with Ruqyah according to the Qur’aan and Sunnah. Telephone/W

Fabian Mark Fabian Mark
Ikorodu, 102222

mit Kraft wachsen wir