Jomiloju Glory

Simple and intelligent person, these site will make you learn and laugh.

24/05/2024
Photos from Jomiloju Glory's post 23/05/2024

Few days to go

Photos from Jomiloju Glory's post 20/09/2023

It been a while here
Let me drop something here,,
Everybody is faking us let me fake you too.
Follow and like my page too

29/04/2023

Fake life

06/11/2022

Invite your friends to follow my
Page Jomiloju Glory.

Happy Sunday to you all
Jommy care๐Ÿ’‹๐Ÿ’‹๐Ÿ’•๐Ÿ’•

03/11/2022

๐Ÿ•ฏ๏ธ๐Ÿ•ฏ๏ธ

Emi naa dabi ogbon fun awon obi mi, mo paro fun won pe mo get admission si LAGOS STATE UNIVERSITY, inu won dun bi mummy mi ti ko sile be ni won ko jade funmi, orisirisi nkan ni won ra funmi, kani mo ri University wo ni bawo ni ko ba se dun to bi awon obi mi se ko nkan funmi, won ko gbogbo nkan ti won ra funmi,, mo pe okan lara awon ore mi to ti lo si Eko ko bami wa ile bo ti bami rile ni mo ti so fun awon obi mi won San owo ile mo kuro ni Abuja mo gba EKO lo, inu mi dun die ko dun denu ni,, emi na gbe ile ti ore mi gba funmi,, larin osu kan mo ti gbe ironu Tunrayo kuro lokan, nigba ti Tunrayo ko gbe calls mi mon, min mon nkan to de ti ko fi gbe calls mi mon,, mo ba igbese aye mi lo werewere,, ore mi Samson tun introduce lady kan simi, nigba ti ko si enikan pelu mi naa tele, ko ma se emi nikan, mo gba lati ma ba lady yen soro, ore mi yi ti wo school, sugbon o ma wa mi wa lekokan igba mi o ma sun,, lojo kan ni mo pe Tife lady ti ore mi introduce simi, mo pe Tife lati wa sun si odo mi Tife na ko jiyen,, ago meje ale Tife ti de ile mi, inu mi dun bi mo ti ri Tife,,, Tife ma rewa o pupa ferefe, ko ga ju ko kuru ju o ri ni iwonba, Tife sese jade secondary School ni, oun na fe se Neco tori ko ni Weac,, Tife wa si ile mi igba ti asiko ounje to mo ni ki Tife ko je ka lo ra ounje je, Tife yari o ni oun ma dana ounje ni, Tife wo kitchen lati dana, larin wakati melo kan tife se white ๐Ÿš o din ata si ede, ponmo wa ninu ata ti Tife din simi lenu, emi ati Tife jo jeun papo ni se ni inu mi dun a se obinrin to tun da ju Tunrayo lo wa, ba ti jeun tan, ni mo ti wi fun Tife ki lo bomi Sara,, Tife wa tan o tun wo a*o wo bra leyin ti Tife wa tan,, mo wi fun Tife ki ni itumo gbogbo yen, ki lo mu to tun fi wo a*o sun, o tun wa wo bra na, igba ti o mon pe o ma wa gbogbo awon nkan yi sun ki lo wa se, ounje nikan lo wa bami se nile, Tife ko mon nkan to fe so, mo ni Tife o ya lo bo awon nkan to wo yi sile.

Ki lo wa sele mo n bo.
E jo gbogbo ile e ma binu pe e ri owo mi, ise lo po die funmi ni.

Don't forget to follow me on my page Jomiloju Glory just follow and like it.
Invite your friends to follow me up am not forget you guys oooo.

29/10/2022

If you invited your friends yesterday, to follow Jomiloju Glory
Inbox me to collect your card

28/10/2022

Invite your friends to follow Jomiloju Glory Page.
And win recharge card tonight ๐Ÿ’ƒ๐Ÿ’ƒ
Give away recharge card๐Ÿ˜๐Ÿ˜

28/10/2022

๐Ÿ•ฏ๏ธ๐Ÿ•ฏ๏ธ

Leyin ti emi ati Tunrayo ti ni nkan po bayi lati gba gbongan(hall) yara idanwo lo ta fi kuro nibe nkan ti emi ati Tunrayo jo ni,, ni mon ro idanwo ti mo ko kan mo kan fi okan gbe ni ti mo ba ti ronu lo bayi erin ni mo rin,, awon nkan yi ni mo se ti a fi pari idanwo, emi ati Tunrayo ko wa fi ara wa sile,,, gbogbo bi awon obi mi to bami so to mi gbo si won lenu, mo di olu wonkoko mo Tunrayo, oro emi ati Tunrayo wa dabi, egusi tooro Mon iyan(pounded yam), eni ti mi kan ro ka jo ma ji ara wa je, ti ife re wa gbile lokan aya mi,, omo odun melo nimi nigba na, mi ti ju omo odun merindinlogun(16) ti ife obinrin ti wa gba okan mi bayi,, igba ti asiko ati gba JAMB,,, emi gan mi mon pe o ti jade baba, mi lo wa so funmi pe se mi lo si school mon,, tori oro mi ti koja afenuso,, mo ni daddy se JAMB ti jade ni, ako igbaju ni baba mi funmi,, won ni ko ti jade lawon so funmi, aro ono keji emi pelu Tunrayo la jo lo gba JAMB,, mo bi Tunrayo lere se oun ko gba ni, Tunrayo ni ko si owo(money) ti oun le fi gba mo ba ni ki ba san owo, Tunrayo ko jale o ni kin ma san, ki ko owo wa, oun ma lo gba nibo min,,, mo ko owo fun Tunrayo o si gba lowo mi,, mo mu school to wumi, ati nkan ti mo feblo read, mo like ise lawyer gan, oun ni mo mu ni University, ti mo si mu MASS COMMUNICATION, fun Polytechnic,,, eleketa ni mo ti mu Languages, iyen ti mo ba lo si College of Education,, gbogbo ero okan temi ko ju University lo tori Law lo wumi ki kan. Ba ti kuro ni Tutorial ti mo ti gba JAMB, ile wa l gba lo tarata,, ero okan temi ni pe awon obi mi ma ti gba ibise won lo,, looto ko si daddy nile, mummy fe jade lemi ati Tunrayo wole,, bi mummy ti ri Tunrayo ni mummy mi ti pe, mummy mi pe Tunrayo won ni ko ni ise to let ma ba iya re se,, to fi tele okunrin kiri,,, mummy mi pariwo mon Tunrayo lori, won wo Tunrayo mon, be ni won so fun Tunrayo pe deyin leyin omo mi ma ba aye omo mi je,, iya mi le Tunrayo jade, mi so fun mummy mi ju ki won fi omo olomo sile lo, igba ti won le Tunrayo bosita mo gba tele Tunrayo,, bee ni mummy mi pemi, Lekan!!! Olamilekan!!! Mi ma da iya mi lohun, emi na sare si gate mo bere sini pariwo Tunrayo!!! Eyin ni Tunrayo wo ko duro mo sare๐Ÿƒ๐Ÿƒ emi mi fe bo, igba ti Tunrayo ri pe mo sare๐Ÿƒ๐Ÿƒ bo lo ba da okada๐Ÿšฒ๐Ÿšฒ duro,, bi mo ti pade leyin Tunrayo niyen, mo mu ori sona ile, bi mo ti dele bayi.

Ki lo wa sele.
A ku ola Jimoh oni emi wa ma se pupo re laye.

27/10/2022

Ikan ninu awon akeko Akanji, bi Akanji lere ibeere, Oluko wa omo melo ni awon obi yin bi, ati pe gan e ti so oruko yin fun wa, Akanji ni, e bami fun Adisa latewo,, gbogbo yin le fi okan bami lo, ma dayin lohun awon nkan te bimi, emi nikan ko ni iya mi bi, omo meji ni awoj obi mi bi, emi ni abi gbeyin, obinrin ni egbon, Tundun loruko egbon mi, bi odun mewa ni egbon mi gba lowo mi, ki won to bi emi, Olalekan ni mon je inu awon obi mi dun pe won tun ri omo kan bi si,, eyi lo fa ti awon obi mi fi ma kemi loju nimu, nkan ti mo ba so ni gbogbo wa ma mu se, ti mo fi jade primary school, kerekere emi na di,, eni to wa secondary school,,, mo ti gbon dada emi ati egbon mi la dijo lo si school olowo nla kan to wa nilu Abuja, motor lo gbe wa lo,,, motor lo gbe wa bo inu, nigba ti ma fi jade school mo ti di gende dada egbon mi ti jade school ni tiwon, emi nkan lo kun, mo ti balaga diedie, mo lero pe gbogbo yin le ti gbon tori kosi omode ninu yin, ko si omo odun mewa ninu yin, tori gbogbo yin le ti ri goloto, omo odun mejila lo kere ninu yin, nkan ti mo so lo ni pe, emi na ti pe ore binrin, mo ti ni ore obinrin, eni ti mo koko ko enu ife(love๐Ÿ’•๐Ÿ’•) Motunrayo loruko re mo ma nife omo yi bi oju Tunrayo mi owon mo nife gan bi eyin ti fe enu, ko si eni ti ko mon pe mo fe Tunrayo,, sugbon ti won ba bi wa lere mo ma so fun won pe ore lasan ni wa, ki won ma ba mon tori ile_iwe ni a si wa, a mura ati se idanwo asekagba ni,, mo ti ni lokan iru ise ti mo fe yan layo ti mo ba ti pari secondary school mi, Lawyer lo wumi gan,, ojo to a fe bere idanwo asekagba yi ni mo ba Tunrayo ni nkan po,, o wami wa sile awon obi mi gan ti da mon Tori ko sese ma wa si ile wa, bo ti wa si ile wa bayi ni mo ti ni ko je ka jo jade, a kuro nile a gba ile _itura kan lo ibe ni mo ti siso loju egun Tunrayo,, emi ati Tunrayo jo ni nkan po,,, mi ni lokan lati fe Tunrayo sugbon mo fe ma fi ibalopo wa ranti re ni,, sugbon mo nife Motunrayo looto,,, oro beyin yo nigba ti mo ba Tunrayo ni nkan po tan.

Ki lo wa sele mo n bo
E ma fi okan bami lo,,,

Want your public figure to be the top-listed Public Figure in Ikeja?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Videos (show all)

Fake life

Category

Telephone

Address

Ikeja

Other Writers in Ikeja (show all)
Babalogbon Busuyi Akiola Babalogbon Busuyi Akiola
Ikeja

better to be late than be a late.

Daily Digest Daily Digest
Ikeja

Daily Digestion

Prymo Studio Prymo Studio
Ikeja

To give basic information on the art of film making starting from how to script a movie, Write, produce and upload quality short films to the amusement and pleasure of our audience

Penelssy Scripts Penelssy Scripts
Kodesoh Street
Ikeja, 100271

CVs. SOPs. Articles. Stories. Business Plans.

Hโ€ขeโ€ขrโ€ข Hโ€ขeโ€ขrโ€ข
Ikeja

A place for you to talk about your problems, life and many more..... Hope you have a fun time......

African Sounds And Stories African Sounds And Stories
Ikeja
Ikeja

This page serves you amazing African stories that teaches moral lessons and promotes African culture.

Akin Adeoya Akin Adeoya
7 Obokun Close
Ikeja, 10001

Informed news and commentary on Brands and Products. Advertising and marketing campaign reviews. How to create, enhance and scale brands through imaginative strategy.

Sam Jindu Sam Jindu
No 1/3Awoshika Bustop Opebi
Ikeja, 100212

inspirational summary of books and political stuff's

Tomiwa_bl Tomiwa_bl
Ikeja

NOT JUST WRITE๐Ÿ™… IT'S CREATIVITY IN WRITING๐Ÿ“’๐Ÿ–‹๏ธ

Selah Moments Selah Moments
Ikeja
Ikeja, 100271

Selah Moments is designed to inspire hope and encourage people to lead purposeful lives.

Promise Patrick Promise Patrick
Ikeja

I Will Tell You What You Need To Know

Sadiq Lasisi Page Sadiq Lasisi Page
Ikeja

Promote your page here!!!